Текст песни Se Bo'timo - Brymo
Ijapa
o
n'ibi
ti
o
n
lo
Kele
kele,
o
n
rin,
o
n
lo
Ara
ile
n
yimu,
o
n
lo
Ero
wa,
ero
lo,
o
n
lo
Ko
gba
agidi
O
ro
bi
A,
B,
D
Ti
o
ba
koju
mo
tie
Ti
mo
koju
mo
temi
Bi
a
ba
fi
eyin
si
owo
otun,
Ki
a
feyin
sowo
osi,
Ki
awa
f'eyin
rin
lati
ahin
titi
de
iseyin
Eni
ma
yini,
a
yini
Eni
o
ni
yini,
Ko
ni
yini
Se
bo'timo
ore
Se
bo'timo
ore
mi
Se
bo'timo
mama
Se
bo'timo
baba
mi
Won
n
tan
e
Dakun
ye
maa
tan
ara
re
T'ire
n
T'ire
Ye
ma
ko
ara
re
Bi
o
ba
sare,
bo
subu
Iwo
lo
lara
re
Bi
o
le,
bi
o
ro
Ore,
ma
paara
ire
Ko
gba
agidi
O
ro
bi
A,
B,
D
Ti
o
ba
koju
mo
tie
Ti
mo
koju
mo
temi
Bi
a
ba
fi
eyin
si
owo
otun,
Ki
a
feyin
sowo
osi,
Ki
awa
f'eyin
rin
lati
ahin
titi
de
iseyin
Eni
ma
yini,
a
yini
Eni
o
ni
yini,
Ko
ni
yini
Se
bo'timo
ore
Se
bo'timo
ore
mi
Se
bo'timo
mama
Se
bo'timo
baba
mi
1 Truthfully
2 Money Ft. David
3 Dear Titilope
4 Eko
5 Grand Pa
6 Down
7 Cheap Wine
8 Purple Jar
9 Everyone Gets to Die
10 Se Bo'timo
11 M, D & S
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.