Dagrin - Kekere текст песни

Текст песни Kekere - Dagrin



Won fe sere, won sope mo
Kere, won ma fe invite mi
Ke, won ma sare, ah!
Won ni were oo
Won sope mo kere, kekeke
Labere kere
Awon to jepe w'on le sere bi mo se nsere
Awon tojepe tiwon ba ri
Akeke won ma sare
Awon toba jepe tiwon ba l'aroma won ni were
Were re o
Were were re o
Were re o
Were were re o
Won tun ti de, emi mofe
Sanjo bi obasanjo
Kon se iro, eni ti o ba ra iro kole ra
òtò
Kati mo ibi to to gba kade mo ona
T'oto Mo nsako tori mo l'awon to yii lowo bi
Opolo se n sako niwaju elegusi
Dollar!
Gbogbo wa lafe je dollar patapat ka wa lo se lodo mallam
Taba kowo yen de, kawa ma f'owo yen cha-cha
Inshort, gbogbo wa la fe di millionaire.




Dagrin - The Genesis of C.E.O
Альбом The Genesis of C.E.O
дата релиза
22-07-2016




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.