Danny S - Hello текст песни

Текст песни Hello - Danny S



Hello my neighbor
Hello
(How are you)
Saola saola
Ijushaga ijushaga (how you dey dey)
Call me Danny s o (how are You)
Hello my neighbor
Àṣírí àbò
Halabamusa
Ehe ehe
Hello my neighbor
Àṣírí ábò
Halabamusa
Ṣeke ṣeke bula
E ma kátan sókè
E ma halleluyah
I thank God oo
Àṣírí ábò
Halabamusa
mi ten million
Ti n ba gbowó ma dápadà
E wo awọn ọmọ ológo
Bán se ń bẹni mòróró
Eni pawá (Eni pawá)
Àwa náà o ni pàyàn (a o ni pàyàn)
Ọjà o ni jẹ (ko ni jẹ wá)
Àwa náà o ni jèyàn (a o ni jèyàn)
Ta jẹ lówó (Ta jẹ lówó)
E jọ e sanwó mi (E jọ e sanwó mi)
Who dey hold my money (Who dey hold my money)
I beg pay my money (I beg pay my money)
Óse kókó (Óse kókó)
Fùrọ' n jẹ kókò (Fùrọ' n jẹ kókò)
Owó ṣe kókó (Owó ṣe kókó)
Èkó wèjèlè (Èkó wèjèlè)
Hello my neighbor 2ce
Àṣírí ábò 2ce
Halabamusa 2ce
Ṣeke ṣeke búlà (ehh)
E kátan sókè (eh eh)
Ema halleluyah (ehhh)
I thank God o
Asiri ábò
Halabamusa
(Watch kòrògbé)
Ọya wogbe e (Ọya wogbe e)
Pariwo neighbor e (Pariwo neighbor e)
So le mi ten million
Mo ma ṣe return (Mo ma ṣe return)
Watch your side (Watch your side)
Pariwo neighbor e (Pariwo neighbor e)
So le mi ten million
Mo ma ṣe return (Mo ma ṣe return)
Àwọn kan lówó
Èmi gan-an ma lówó
Àwọn kan lọla
Èmi gan-an ma lọla
Halabamusa
Àṣírí ábò
Halabamusa (eh eh)
Hello my neighbor
Àṣírí ábò
Halabamusa (halabaa)
Hello my neighbor
Àṣírí ábò
Halabamusa (eh eh)
Hello my neighbor
Àṣírí ábò
Halabamusa
All the way from iju
Àwọn ọmọ Shaolin temple
All the way from ìlú sakusaku
Àwọn ọmọ ìjọba guruma gúsù
Àwa kìí ṣọmọ jakujaku
Sòkó ń o
Call me Danny s o
Booster
Osha booster
Virgin producer
Soo



Авторы: Lionel B. Jr. Richie


Danny S - Hello - Single
Альбом Hello - Single
дата релиза
12-11-2019

1 Hello




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.