Fela Kuti - Lover текст песни

Текст песни Lover - Fela Kuti



Ololufe mi, ti e ni mo fe
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Ololufe mi, mi o se tiwon mo
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Wa f'enu ko mi l'enu, oh-oh
Wa f'ara ro mi l'ara o
Eh, eh, eh, eh, eh, eh
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Ololufe mi, ti e ni mo fe
Alayanfe mi, mi o se tiwon mo
Alayanfe mi, ti e ni mo fe
Wa f'enu ko mi l'enu
Wa f'ara ro mi l'ara o
Oh, oh, oh, oh, oh



Авторы: Fela Anikulapo Kuti


Fela Kuti - The '69 Los Angeles Sessions
Альбом The '69 Los Angeles Sessions
дата релиза
04-03-2013




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.