King Sunny Ade - Appreciation текст песни

Текст песни Appreciation - King Sunny Ade



Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
ènìyàn kọ' l'Ọlọ'run míí o
ènìyàn kọ' l'Ọlọ'run míí
ènìyàn kọ' l'Ọlọ'run míí o
ènìyàn kọ' l'Ọlọ'run míí
Ẹ'dá l'óń gbàgbé, Olúwa gbàgbé ẹnìkan
ènìyàn kọ' l'Ọlọ'run míí
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Ẹní ń ràròjinlẹ' loleè mọpẹ'dá
Èmi yóó gbe ga ò Olúuwa
Ẹní ń ràròjinlẹ' loleè mọpẹ'dá
Èmi yóó gbe ga ò Olúuwa
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Appreciation
Mo dúpẹ', Oníbúọrẹ Bàbá gbopẹ' mi
Ìgbòkègbodò mi
Okòjẹ sófo, modúpẹ'
Ìgbòkègbodò mi o
Okòjẹ sófo, modúpẹ'
(Wí bẹ'ẹ') Ẹ'dákun, lùlù fún mi ò
Kín f'Ọ'lọ'run mi
Lùlù fún mi (kin gbọ')
Lùlù fún mi
Kín fún Baba
lùlù fún mi
Kín f'Ọ'lọ'run mi
Lùlù fún mi (kin gbọ')
Lùlù fún mi
Kín fún Baba
Ore Ọlọ'run pọ' lórí mi ò
Óyẹ kín fún Babaà mi
Lùlù fún mi
Lùlù fún mi
Kín fún Baba
Àní, ore Ọlọ'run pọ' lórí mi ò
Óyẹ kín fún Baba
Lùlù fún mi
Lùlù fún mi
Kín fún Baba
Ẹ'yin onílù ẹlùlù fún mi
Kín fún Baba
Lùlù fún mi
Lùlù fún mi
Kín fún Baba...



Авторы: Maurice Rivera, Josh Kouzomis


King Sunny Ade - Seven Degrees North
Альбом Seven Degrees North
дата релиза
20-06-2000




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.