Tim Godfrey & Xtreme - Oriki - Live текст песни

Текст песни Oriki - Live - Tim Godfrey & Xtreme



ORIKI by Tim Godfrey & Extreme crew
Choral 1:
Ka-biyesi atoperi Eledumare mi se
Ka-biyesi agba nla atoperi Eledumare mi
Se
Baba mi awimayehun, Baba mi awilese
Baba mi aselewi, Baba mi, Baba nla ti
Ngbani
Gbani Gbani lojo isoro, eleti gbohun
Gbaroye
Afetilukara bi ajere, eru jeje leti okun
Pupa
Oba to tele bi eni nteni, Ota somo bi eni
Taso
Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai
Choral 2:
Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Eyin lakoda, eyin laseda, eyin laweda
Eyin lameda, ogbagba tirin gbagba
Alagbada ina, alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin
Edumare moti mope mi wa feni tope ye
Fun
Moti fiyin feni tiyin se tire o
Choral 3:
Eni to n se mimo, to n je mimo, to n mu
Mimo
To n gbe bi mimo, to niwa mimo, Alade
Ogo
Talaba fi o we, na you bi ano, na you bi
Oni
Na u tuni lola, ope ye o o Baba, Edumare
Gbope wa
Tire ni o, tire ni o
Mo fi sile fun o
Females: Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Call- my praise
Resp: my praise
Call- Belongs to you
Resp: Belongs to you
Call: Ese
Resp: Ese
Call: Adupe o
Resp: Adupe o
Call: Igwe/6x (nna naba me)
Resp: Igwe



Авторы: Timothy Godfrey, Emmanuel Samuel Giveson


Tim Godfrey & Xtreme - iWorship (Live)
Альбом iWorship (Live)
дата релиза
03-06-2014




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.