Tim Godfrey & Xtreme - Oriki (Reprise) текст песни

Текст песни Oriki (Reprise) - Tim Godfrey & Xtreme



Kabiyesi atoperi Eledumare mi se
Kabiyesi agba nla atoperi Eledumare mi
Baba mi awimayehun
Baba mi awilese OH
Baba mi aselewi Baba mi ogbagba nla ti ngbani Gbani Gbani lojo isoro
Eleti gbohun gbaroye
Abetilukara bi ajere Eru jeje leti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni
Ota somo bi eni taso
Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai...
TESTIFY!!!!
Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Iba akoda
Iba aseda
Iba aweda
Iba ameda
Ogbagba tiri gbagba Alagbada ina Alawotele oorun Alade
Gbedegbede bi eni n layin Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun
Moti fiyin feni tiyin nse tire o
Eni to n se mimo
To n je mimo
To n mu mimo
To n gbe bi mimo
To niwa mimo Alade ogo
Talaba fi o we
Na you bi ano(yesterday)
Na you bi oni(today) Na u tuni lola
Ope ye o o Baba Edumare gbope wa...
Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
My praise
My praise
Belongs to you Belongs to you
Ese
Ese
Adupe o
Adupe o
Igwe
Mo fi sile fun o
Females: Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
(Modulation)
(Modulation)
(Modulation)
Call- my praise
Resp: my praise
Call- Belongs to you
Resp: Belongs to you
Call: Ese
Resp: Ese
Call: Adupe o
Resp: Adupe o
Kabiyesi atoperi Eledumare mi se
Kabiyesi agba nla atoperi Eledumare mi
Baba mi awimayehun
Baba mi awilese OH
Baba mi aselewi Baba mi ogbagba nla ti ngbani Gbani Gbani lojo isoro
Eleti gbohun gbaroye
Abetilukara bi ajere Eru jeje leti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni
Ota somo bi eni taso
Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai...
TESTIFY!!!!
Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Iba akoda
Iba aseda
Iba aweda
Iba ameda
Ogbagba tiri gbagba Alagbada ina Alawotele oorun Alade
Gbedegbede bi eni n layin Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun
Moti fiyin feni tiyin nse tire o
Eni to n se mimo
To n je mimo
To n mu mimo
To n gbe bi mimo
To niwa mimo Alade ogo
Talaba fi o we
Na you bi ano(yesterday)
Na you bi oni(today) Na u tuni lola
Ope ye o o Baba Edumare gbope wa...
(Tire ni o
No fi sole fun oo)
Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
Tire ni o
Tire ni o
My praise
My praise
Belongs to you Belongs to you
Ese
Ese
Adupe o
Adupe o
Igwe



Авторы: Timothy Godfrey, Emmanuel Samuel Giveson


Tim Godfrey & Xtreme - iWorship
Альбом iWorship
дата релиза
18-10-2014




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.