Текст песни Orun Oun Aye - Tope Alabi
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
n
kede
ogo
Re
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
n
kede
ogo
Re
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Didara
orun,
o
n
so
togo
Re
o
Olorun
Ewa
Re
to
yi
aye
ka,
n
so
togo
Re
o
bo
ti
po
to
Gbogbo
eda,
eranko
at'ewebe
n
yin
O
o
Ise
owo
Re
gbogbo
loke
nile,
won
n
yin
O
o
Baba
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
kede
ogo
Re
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Ola
lo
wo
laso,
ogo
lo
fi
pa
kaja
orun
Ipa
ese
Re,
o
n
han
l'ori
apata
Esin
Re
n
fogo
yan,
l'ori
awon
okun
o
Olola
nla
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
j'okele
yo,
ti
n
o
ni
le
juba
Re
Oba
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
kede
ogo
Re
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Gbogbo
eemi
inu
mi,
o
n
yin
O
yato
o,
Olorun
mi
Iwo
to
mu
mi
la
ina
koja,
to
fi
mumi
goke,
kini
mba
fi
fun
O
Kini
mo
to
si
ninu
oore
ofe
ti
mo
ri
gba
lodo
Re
O
ba
aye
mi
da
majemu
lati
'nu
ole
Oro
Re
ye,
o
si
se
Oba
ti
ki
i
dale
oro
Re
Iwariri
ni
n
o
ma
fi
juba
Re
o
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
kede
ogo
Re
Kini
yo
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Orun
oun
aye
kun
fun
ogo
Re
Egbegberun
awon
irawo
kede
ogo
Re
Kinni
o
waa
se
mi,
ti
n
o
ni
le
maa
juba
Re
o
e
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.