Zlatan - Wake Up текст песни

Текст песни Wake Up - Zlatan



Ayé
Wọ
Ēmi sokale
Ibile
sokale
Kapachimerimeripako
Oya when I wake up in the morning (spellz)
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba debi
Kinto gba debi
when I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba debi
Kinto gba debi
(Jomor)
Ọdọ yi gba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
lo yo mi oh yeahh
Ọdọ yi gba debi
Shebi adura momsi àti popsi mi
ma lọ yo mi
kinto gba debi
Ah ah ah ah
Kúrò bẹ
Wọ
Them say love na one tin tin
Na so this year gon bintin
I travel nígbà hẹn ade mọ ni olówó
ti kpa ma fi àkara fún mẹ koko
Everyday lafin she adura
Fún Jésù oriwa kin àwa jẹ nepa wa ge ino
Showers of blessing le npe
Ojo ti kun palour wa
Tori every time tio ojo ba rọ lo ma leak lati roof wa
And I wan build this legacy for my family
Before I komot for house I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbe lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ijeta nimoni ko dahun konde pick call
When I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny (ah)
Kindo gba debi
Jomor
when I wake up in the morning
Modupé fi Ọlọrun
It wasn't really funny
Kinto gba debi
Kinto gba debi
Ọdọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
lo yo mi
Ọdọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
ma lo yo mi
kinto gba debi
Wọ èmi rẹ
Mo jẹ ẹni fresh
ēmi re mo wa dẹni fresh
Wọ èmi èmi rẹ
Mo jẹ ẹni fresh
ēmi re mo wa dẹni fresh
Èmi rẹ imọlẹ ti olùwà gbọ gbọ fi
Mọn hussle fún Toronto oh
nínú òtútù ni mọn kólé
Ki ra igbo fún
Mọn ti fresh telé telé woni ongberun
Awọn wọnyi la abo
And I wan build this legacy for my family
Before I komot for house I promise say them go be proud of me
Jésù nìkan mogbe lẹyìn é kòsí ẹlomi
Lati ijeta nimoni ko dahun konde pick call
Ọdọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
lo yo mi
kinto gba debi
Ọdọ yi gba debi (ayọ mi yin ton)
Shebi adura momsi àti popsi mi
lo yo mi
kinto gba debi
Spellz




Zlatan - Zanku
Альбом Zanku
дата релиза
01-11-2019




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.