Lyrics Ololufe (feat. Wande Coal) [Mixed] - DJ Neptune
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
rẹ
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
rẹ
(giddem!)
Hmm,
sọ
fun
wọn
mo
n'ifẹ
Mo
ni,
"Fọlashade"
Sọ
fun
ẹ
pe
mo
n'ifẹ,
mo
n'ifẹ
gan
ni
o
Layẹmi,
Olayẹmi,
mo
n'ifẹ
Funkẹ,
sọ
fun
ẹ,
"Mo
n'ifẹ"
Titilọla,
hmm,
sọ
fun
ẹ,
"Mo
n'ifẹ"
Mo
ni,
"Fọlashade"
Sọ
fún
ẹ
pe
mo
n'ifẹ,
mo
n'ifẹ
gan
ni
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
rẹ
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
re
Ko,
ko,
ko,
ko
Konkobilo,
ko,
ko,
ko
O
wá
fẹ
pàdé
mí
ní
ìsàlẹ
Ò
yẹ
ká
fún
konkobilo
Ko,
ko,
ko,
ko
O
wa
fẹ
jẹ
ko,
ko,
ko,
ko
Moni
ko
pàdé
mí
ní
ìsàlẹ
Ìyẹn
gan
lo
n
ṣe
ko-ko
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
rẹ
Iwọ
l'ololufẹ,
my
darling
Iwọ
l'ololufẹ
mi,
mo
n'ifẹ
rẹ
(giddem...)
Attention! Feel free to leave feedback.