FTK - Ise Oluwa Lyrics

Lyrics Ise Oluwa - FTK



Iyeeee Moyashau, ọba ṣe èyí òwú,... Ọba alagbara
Mi ò to o lérè sugbon gba mi láyé kin leyi o
Pé, Ṣe pín dọ'gba, sho ọba ayé kan ma binu
Ṣe pin kárí ṣe alágbára ayé kan ma bínú ni
Cos I dont know why, t'àwọn kan je ti àwọn kan o ri,
Cos I dont know why ti àwọn kan jọba àwọn kan ṣe eru,
Toba sọ w'oni ayé ṣe gba ni yẹn o
Mon fi omijé ó, Dákun mi lọun bàbà
Nibo lalanu mi wá, ti ara rẹ dide
lolore mi ó, ti ara rẹ j'eniyan
Ẹrú ayanmo di lomi ó wúwo, owuw o wúwo oo
Ẹrú ti kadara di lomi ó wuwo, ó ju ojo orí mi lo
...Moyashau
Ọba ṣe èyí òwú, mi ò kúkú sọ èyí ṣe si mi oda,
Àmọ' bin ṣe é óò, ojú kúrò lásise mi
jẹ ẹsẹ,
àwọn ti àwa wà, máa bere ẹsẹ wọn lórí mi mo,
Ayé ó rurun fún ẹni ó nìkan.
Olóore dìde fún mi, gbé alanu dìde o,
Kín yẹ gbẹ ilé aye alaisi mo,
Kín yẹ jẹun alaisi mo,
Kín yẹ rìn ẹni àyè e, Ọlọ'run jọ.
Boba je kadara mi ni ó dà, Ọlọ'run ban tún ṣe.
Atún orí ẹni tio súwon ṣe, ìwọ ni.
Mo mọ ó, olè ṣe ju bẹlo.
aya yẹ lara mo ó,
Ọlọ'run gbogbo ẹran ara.
lójú rẹ wà, Dákun dáhùn oro mi ò.
Ọba gb'orí ite pàṣẹ, oya pàṣẹ anu ayé mi Ọlọ'run. Eh eh Baba o
Till end




FTK - The Crown
Album The Crown
date of release
22-09-2015




Attention! Feel free to leave feedback.