Lyrics Ara Ma Nfe Sinmi - King Sunny Ade
Ọrẹ
rẹ
die
bínú
bínú
woni
mo
ku
Iya
gbó
ni
lè
ebi
ń
wá
ní
kiri
Iya
gbó
ni
lè
ọrẹ
ń
wá
ní
kiri
Tebi
Tara
tore,
won
temi
lago
Lai
mo
wípé
Mi
ò
báwọn
wá,
ẹ
mi
ò
ní
báwọn
lo
Mi
ò
báwọn
wá,
ẹ
mi
ò
ní
báwọn
lo
Ototo
larin
wá,
Ototo
larin
wá
Ṣebi
ile
ayé,
ilé
ayé,
ilé
ayé
yí
là
pàdé
ara
wa
Ọrẹ
wá,
ọjọ'
lọ
npe
ó,
Ìpàdé
kìí
jinna
ọjọ'
lọ
npe
ó,
Ìpàdé
kìí
jinna
Ìkà
eda
tó
fowo
padà
Ọlọ'run
loju
Ìkà
eda
tó
fowo
padà
Ọlọ'run
loju
Ìdájọ'
ó
jìnnà,
idajo
ó
jìnnà
Aye
ẹ
má
dalekun
Torí
mi
ò
báwọn
wá,
èmi
ò
ní
báwọn
lo
Mi
ò
báwọn
wá,
èmi
ó
ní
báwọn
lo
Torí,
òtoto
larin
wa,
òtoto
larin
wá
Ṣebi
ile
ayé,
ilé
ayé,
ilé
ayé
yí
là
pàdé
ara
wa
Ayéeeeeeee,
Ayee
yiii
oooo
Ayéeeeeeee,
Ayee
yiii
oooo
Ayé
toto
Ọjọ'
ó
rò,
ìṣù
ó
tà,
àgbàdo
ó
gbó
oo
Ọjọ'
ó
rò,
ìṣù
ó
tà,
àgbàdo
ó
gbó
oo
Ọjọ'
ó
rò
se,
ìṣù
ó
tà,
àgbàdo
ó
gbó
oo
Ara
máa
ń
fẹ',
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
E
rọra
ṣe
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
E
rọra
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ara
máa
ń
fẹẹ
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Àní
ara
máa
ń
fẹ'
ó
jare
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Jìgìjìgì
lojojumo
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ọrẹ
wá
jìgìjìgì
lojojumo
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ifakafiki
làálàá
lè
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Jìgìjìgì
lojojumo
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ará
máa
ń
fẹ'
ó
jare
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ifakafiki
lórí
ẹni
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
Ará
máa
ń
fẹ'
(ara
máa
ń
fẹ'
simi)
(End.)
1 E Dide E Mujo
2 Ara Ma Nfe Sinmi
3 Oshodi Oke
4 Orisun Iye
5 Ose Ose
6 Yoruba
7 Ope Oku
8 Dance Dance Dance
9 My Mother
10 Alashe L'Aiye
11 Omode O'Mela
12 Enia L'Asho Mi
13 Ode La Alaga
Attention! Feel free to leave feedback.