King Sunny Ade - Ode La Alaga Lyrics

Lyrics Ode La Alaga - King Sunny Ade



Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re wale
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re wale
Ode Le alaga, ode Le alaga
Oyele mori re, oyele mori re
Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haa, Igbeyin lodun a haa
Tori alase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale
YeYe alala ọtọ bi mo re, igbeyin lo mo ju o jàre
Baba ọlọrun é to mo re, igbeyin lo mo ju o jàre
Tori
Ọba ma fi mi bin se wa rẹ mi eyin are ololoriwo
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Tori ala lase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale
Oluwa Maje ka o jàre
Oluwa Maje ka lale
Igbeyin lo dun ara ayé o
Oluwa Maje ka lale
Igbeyin lo mo dun ọtọ bi mo yin lo jàre
Oluwa Maje ka lale
Iya ọlọmọ toju omo rẹ
Igbeyin lodun a haa Igbeyin lodun
Igbeyin lodun a haaa,Igbeyin lodun
Tori alase bimo o, Igbeyin lodun
Oluwa Maje ki a de lale



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - E Dide (Get Up)
Album E Dide (Get Up)
date of release
29-07-2008




Attention! Feel free to leave feedback.