King Sunny Ade - Bombibele Horojo Lyrics

Lyrics Bombibele Horojo - King Sunny Ade



B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele ba n bi'nu, alabaja a nawo gan ni
Alade ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo
B'oni pele ba n bi'nu, alabaja a fa mora ni
African beat tun gbede, ori o gbodo fo
B'oni pele n roju, alabaja a fa mora
Sunny ti de, ori o gbudo fo



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - The Best of the Classic Years
Album The Best of the Classic Years
date of release
20-06-2005




Attention! Feel free to leave feedback.