King Sunny Ade - Oro Towo Baseti Lyrics

Lyrics Oro Towo Baseti - King Sunny Ade



Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
Maa je owo gbeyin rara tori
Oro towo ba seti ile lo n gbe
Ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
Owo lo n se nkan ire
Owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
Kin rowo fi jaye
Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
Maa je owo gbeyin rara tori
Oro towo ba seti ile lo n gbe
Ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
Owo lo n se nkan ire
Owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
Kin rowo fi jaye
Bi eniyan ba mbe laye
Bi o ba lowo rara
Adabi r'eni to ti ku
Ti won o ti gbe si koto
Laye mi se
Adura wa ni pe
Ohun gbogbo t'Oluwa yo se fun wa
Maa je owo gbeyin rara tori
Oro towo ba seti ile lo n gbe
Ewa wo n towo se, nile aye tawa yi
Owo lo n se nkan ire
Owo lo n se nkan gidi
Edumare funmi ni temi o
Kin rowo fi jaye



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - The Best of the Classic Years
Album The Best of the Classic Years
date of release
20-06-2005




Attention! Feel free to leave feedback.