LC Beatz - Adua Lyrics

Lyrics Adua - Lc Beatz



A wa ko dupe lowo baba
Fun ore nla la re Laye wa
Oya baba loke ese
Gbope wa gbayin wa
Won ni ko sami lojos
O lo n se fari gan
Ye ma pemi loloti
TI n ba ti n se bayi gan
Awa ti ani emi mimo
La n se ifedefo
La n se bayi gan



Writer(s): Oluwaseyi John Ajala


LC Beatz - GaGa: God and God Alone, Vol. 1
Album GaGa: God and God Alone, Vol. 1
date of release
14-10-2016




Attention! Feel free to leave feedback.