LC Beatz - Pewon Lyrics

Lyrics Pewon - Lc Beatz



Ah! Lc beatz!
Ah! Ore to nja sire, mo pewon
Ore to nga jore, mo pewon
Ore toluwa se, mo pewon
Ore to nje tire, mo pewon
Ah! Pewon! Pe-Pewon!
Ah! Pewon! (Oya! Pewon!)
Ah! Pewon! Pewon! Pewon! Pewon! (Oya! Sare! Tete mo pewon!)
Ah! Pewon! Pewon! Pewon! Pewon! (Oya! Tete tete, je a pewon!)
Ah! Pewon! Pewon! Pewon! Pewon! (Oya! Tete tete, sa moo pewon!)
Emi gan ti de moti mo wassup, Ah! Mo pewon
Ore ni gusu lariwa ni wo orun, nila orun, mo pewon
Ore to tosi mi as omo Jesu, Ah! Mo pewon
Lofurufu, ile, lori omi, pewon!
Jesu Kristi ahn! Pee!
Fawa soke! Ahn! Pee!
Ore to ti lole, bami fawon soke! Ahn! Ah!
Ape mora eni la npe temidire
Loruko Jesu yen, temi ti dire
Everybody nso wipe (temi dire ahn ahn)
Ape mora eni la npe temidire
Loruko Jesu yen, temi ti dire
Everybody nso wipe (temi dire ahn ahn)
Oh lalala lala
(Back to Chorus)
Ko ni gbeyin, loruko Jesu, temi ko ni gbeyin
Ore to wani waju, afi ki nfa
Oya! Sekeseke!
Afi ki nfa (ahn ahn ahn)
Afi ki ngba (Jesu argh! Ah!)
Pe pe pe pe pe pe...
Ore Monday Tuesday mo pewon
Ore Wednesday Thursday mo pewon
Ore weekend gan mo pewon
Ore ojo isimi pewon
Ore public holiday pewon
Oya pewon o, tete pewon o
Tete pewon o
Pewon o, tete pewon
Loni groovy groovy pewon!
Ah! Pewon! Pe pe pe pewon...



Writer(s): Oluwaseyi John Ajala


LC Beatz - GaGa: God and God Alone, Vol. 1
Album GaGa: God and God Alone, Vol. 1
date of release
14-10-2016




Attention! Feel free to leave feedback.