T-Röd - Lazy Nigerian Youth Lyrics

Lyrics Lazy Nigerian Youth - T-Röd



Ehhh
Yaaa
Hum
What di do
Yaaa
Hum
So èmi ṣì máa sa dua fún àwọn tèmi
Wole ileya Kari gan
Ìjọba feje riwa, ẹri ban ṣe parí gan
Tomode tagba kúrò nilu wọn salo s'Abidjan
Nobody lazy for here even olè wey dey carry gun
Àwọn ọmọ yín overseas, all of them are having fun
And all of my ghetto boys still working under the sun
Koma sere nigboro, ero oro yin ye keto so
EFCC were yẹn na ọ'rọ' yahoo Boys lo ma sọ
Àwọn idiot fellows àwa tán wọn lọ ń sopa
Wọn mon èmi kan san salary fún oga Ọlọpa
Padi mi Pupa dúdú owu lọ
Ẹyin ijoba were yi ejò wúlò fún
Eyan kan billion, Eyan kan trillion
Mo mọ pe dream Eyan kan yín ni zillion
You dey inside AC you talk say na the youth lazy
Inú iná wo, O sure mi Ema de
Ema diwo ẹni body ẹni bama sase sase
Eti gbàgbé nígbà òyìnbó sopolo d'ase
Ejò gbé 36 milly, ejoo ni nibo lowa?
Ko jeje pe Mushin, Bariga Taboshodi lo wa
Oshodi, Oshodi, Oshodi, Oshodi óò, wọlé pelu change ẹ, mio ni
Change óò, to change wọlé óò, mi ò change óò
So, President Buhari ojú tún
Ẹ'fọ'n ẹ'jẹ' coldstone, a tún rowo ra túrari
Ọjọ' jumo ń rerin yín TVC
Ebi ń pa mekunnu ẹni kan ṣe PVC
ìṣe nigboro làwọn graduate fi ń gbé lapi
Tori won mo pe táwọn sase wọn be happy
Aṣo rock láṣebi ń gbé, inú gangan lọ
Naija ni kan ni mo ti gbó penu kininhun lowo
Wọn SAS gboro àwọn yẹn anti robbery
Gbogbo innocent citizens pátá na ti nobi
Meek Mill jáde kúrò prison ó look chubby
May peace be upon my people ẹyin ogologo Anobi
To san ra DJ KHALED ń look fìrìfìrì
Ó digbale agbepo kúrò kirikiri
Ẹ'jẹ' lójú anybody ìyá ń jẹ' gan
To gboro, rẹ ni to lagbo ju Fela Lo
Naija nìkan na ń fún l'award fún corruption
Ko ṣe fault àwọn ìjọba lọpọlọ wọn ṣàn
Kira fún àwọn tèmi
júbà fún àwọn tèmi
Ìwọ gba wire na, invest lo fun awon temi
K'awọn tèmi ó ròhun jẹ je Everyday
Because it's not easy we expect a good day
Ìjọba change lafe, afe changi
Ejo ewa ikan shey si level yi




T-Röd - Lazy Nigerian Youth
Album Lazy Nigerian Youth
date of release
19-07-2018




Attention! Feel free to leave feedback.