Teni - Malaika Lyrics

Lyrics Malaika - Teni



Yi o ti ma loo
Mo l'Olùwà
Bo ti le-le ju, orúkọ rẹ
Eli, Elijah
Eli, Elijah, ah-ah
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli, Elijah o
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
I'm at peace with God, and at peace with myself (uh-whoa, uh-whoa)
I surrender, I surrender
No weapon fashioned against me shall prosper
Back to sender (mo ni back to sender o), back to sender (mó ni back to sender o)
Lord, I give You my heart, and my soul, and devotion
You give me peace of mind
And I see all Your works and the good that You are doing
Ṣebi na You change my life
Ògo ní, ògo ní, ògo fún Baba
Ògo fún Ọmọ
Ògo ní, ògo ní, ògo fún Ọlọrun Ẹmí Mimọ
Ògo ní, ògo ní, ògo fún Bàbá
Ògo fún Ọmọ
Ògo ní, ògo ní, ògo fún Ọlọrun Ẹmí Mimọ
Thank You for the things that You got me through
Na only me and You
I dey cry night, You dey wipe my eyes
Na You dey give me grace o
You say make I get faith o
Make my faith no deflate o
Don't jump from my plate o
People change, but You remain the same o
Àìmọye èyàn to ń lójoojúmọ́
Mi ò yọ wọn, mo ń dúpẹ
Ẹru ń dupẹ ni, mo ń dúpẹ o
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah (eh-eh, eh)
Ọrun ṣi ilẹkun
Malaika sọkalẹ wa
Eli, Elijah o
Eli, Elijah (eh-eh, eh)
Eli, Elijah, ah-ah
Ọrun ṣi bo'lẹ
Malaika sọkalẹ wa
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)
Malaika sọkalẹ wa o (Malaika sọkalẹ wa)



Writer(s): Teni Apata, Oluwademilade Ayobamidele T.a Alabi


Teni - Malaika
Album Malaika
date of release
03-11-2023




Attention! Feel free to leave feedback.