Lyrics Kabi o osi - Tope Alabi
Kabi
o
osi
Kabi
o
osi
Arugbo
ojo,
ad'agba
ma
tepa
Kabi
o
osi
We
worship
you,
kabi
o
osi
We
worship
you,
kabi
o
osi
Arugbo
ojo,
ad'agba
ma
tepa
Kabi
o
osi
Won
o
mu
o
lo
l'edi
ki
won
fi
ewe
akoko
le
o
lori
n'be
Ko
s'awon
to
gbinmo
po
lati
so
pe
e
je
a
fi
joba
Ab'awon
wo
lo
duro
tan
ni
won
a
ma
joba
n'idile
won
gan
Awon
wo
lo
fi
o
je
t'o
fi'n
j'oba
kon
da
wa
l'ohun
Ta
leni
isaju
to
mu
o
wa
s'inu
orun
Ta
leni
to
fa
o
ni
tete
wonu
aye
pe
ko
wa
d'aye
Oya,
k'enikan
fi
baba
tabi
iya
re
han
wa
o,
aare
Kabi
o
osi
Arugbo
ojo
ad'agba
ma
tepa
l'oruko
re
Kabi
o
osi
O
l'oyun
ara
re,
obi'ra
e,
o
s'ora
e
lo'ko
Ipa
ti
o
se
bi
l'eere,
eni
ti
o
se
yi
pada
Ite
re
l'orun
kii
si
onipo
ta
o
le
ro
l'oye
Arugbo
ojo
ni
o,
ad'agba
ma
tepa
o
Ehhh
iwo
ni
ka
bi
o
osi
Riru
omi
okun
po,
nje
won
o
ni
dake
to
ba
l'oto
Iyanrin
nla
tun
wa,
to
ba
k'aye
tan
se
won
o
ni
pare
Igba
t'ohun
gbogbo
ta
ko
ba
di
wiwo
pale
iwo
ni
o
ku
o
Arugbo
ojo,
onilu
a
lu
la'torun
o
Ehh
eh
eh
eh
eh
kabi
o
osi
O
ko
d'aye
eru
b'aye
pe
kilo
fe
wa
ninu
ohun
Igba
to
da
aye
tan,
o
m'ohungbogbo
s'aye
e
kon
ma
j'oko
won
O
ti
n
gbe'bikan
ki
o
to
ko
orun
aare
nla
ni
o,
o
se
tu
Ailetuwo
adahunro
adahunso
Olunkankun
ni
o
Arugbo
ojo,
ad'agba
ma
tepa
ooo
Iwo
ni
ka
bi
o
osi
Omomo
to
mo'yun
sinu
alaboyun
to
f'ori
f'eti
f'enu
si
O
f'imu
o
f'ohungbogbo
sibe
e,
o
de
d'igba
kan
o
bi
Se
bi
bo
ba
pe
ki
mimi
o
ma
mi,
tani
n
jebe
o
Iwo
ni
kabi
o
osi
Agbara
re
po
o
ju
t'ara
lo,
iwo
lo
da
ara
Okun
re
po
ko
de
le
pin,
oni'mi
iye
Iwo
lo
mimi'ye
si
amo
lasan
to
pada
wa
d'eniyan
Ehh
eh
eh
eh
kabi
o
osi
Oba
ti'n
f'oba
je,
oba
to
le
r'oba
l'oye
to
le
ni
ko
ma
mi
mo
Oba
ta
o
gbodo
bi
bo
ba
se'n
sise
owo
re
si
Ojo
n'ro
oye
n'fun
be
l'orun
ran
l'asiko
re
o
Agbara
re
po
o
Kabi
o
osi
Mo
ni
kabi
o
osi
Kabi
o
osi
Kabi
o
osi
Alagbada
ina,
alawotele
oorun
Eh
eh
eh
kabi
o
osi
1 Imole De
2 Logan Ti O De
3 Awa gbe o ga
4 All the Glory
5 Iwo Lawa O Ma Bo
6 Kabi o osi
7 No One Else
8 Eru Re To Ba
9 Olowo Ina
10 We Have Come
11 Emi Mimo
12 Oba mi De
13 Ayo
14 War
15 Alayo
16 Adonai
17 Angeli
Attention! Feel free to leave feedback.