Lyrics L'oro L'ero Ati Ni'se - Tope Alabi
Emi
o
fe
o
oluwa,
agbara
ati
apata
Iwo
ni
igbala
mi,
ilu
olodi
mi
Ile
isho
mi
giga,
ti
owo
ota
ko
le
kan
Ofa
mi
jade
wa
lati
inu
omi
nla
Titi
le
mi
o
fe
lorolero
ni
ise
Loro
lero
ati
ni
ise,
loro
lero
ati
ni
ise
Loro
lero
ati
ni
ise,
Loro
lero
ati
ni
ise
Emi
o
fe
o
oluwa,
iwo
ni
iranwo
mi
Emi
o
gbeke
e
le
igbala
owo
otun
re
Iranwo
re
yo
mumi
duro
shin
shin
Awon
elomiran
gbeke
won
le
keke
ogun
Sugbon
emi
gbekele
lero
ni
ise
Loro
lero
ati
ni
ise,
loro
lero
ati
ni
ise
Loro
lero
ati
ni
ise,
Loro
lero
ati
ni
ise
Emi
o
ma
yo
si
oluwa,
oba
ati
ase
mi
Fibukun
fun
oluwa,
anu
re
duro
titi
Ofi
ade
de
mi,
o
ko
mi
lonare
Ola
ati
ojo
gigun
lo
jogun
fun
mi
Ope
mi
yo
po
loro
lero
nise
Loro
lero
ati
ni
ise,
loro
lero
ati
ni
ise
Loro
lero
ati
ni
ise,
Loro
lero
ati
ni
ise
Attention! Feel free to leave feedback.