9ice - Iwaju paroles de chanson

paroles de chanson Iwaju - 9ice



Iwaju iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwájú laa máa máa lo
Want song, wants flavour
E maa ríran ti n ba k'orin
Mo èèmo l'agege, ajá w'ewu o roso
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Enu eni laa fi ko meejè
Enu eni power
Give me more power, more more blessings
Ti n ba kankun wàá fún mi
Ibéèrè re o, je o leesi
Give me more power, more more blessings
Many wey you don bless, I follow them celebrate
Many wey you give power
Them misuse am we no dae
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Laa máa máa lo
Aro wa ti weere l'aiye
Iwaju ni n máa lo
Lókè, lókè looke ni n máa
B'óta mi p'ogun, p'ogbon won lee lasan
Iwaju n máa lo
Lókè, lókè looke ni n máa
Iná ómó oko ya, l'ómo alè sun isu je
Lókè, lókè looke ni n máa
Iwaju Iwajui
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Want song, wants flavour
E maa ríran ti n ba k'orin
Mo èèmó l'agege, ajá w'ewu o roso
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo
Iwaju Iwaju
Iwaju laa máa máa lo




9ice - Iwaju - Single
Album Iwaju - Single
date de sortie
14-05-2021

1 Iwaju




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.