Asa - Iba (Digital Bonus Track) paroles de chanson

paroles de chanson Iba (Digital Bonus Track) - Asa



Nitori re mo se lo la
Nitori re n mo se n so ge
Nitori re mo se ra moto
Mo wo le, mo boluwa mi soro
Nitori re n mo se wa laiye
Nitori re n mo se wa so sa ra
Nitori re moji lo wu ro
Mo wo aye mi lo de
Aho ha ha a ho
Iba fun eledua
Aho ha ha a ho
Mo wo le mo boluwa mi so ro.
Nitori re n mo n se gbo Iroyin ayo
Lai so wo, lai si nkon nkon
I ya oni la ayo ola o o
Boluwa se wi be na lo ri
Oh oh o wi pe kin ma se beru
Aho ha ha a ho, aho
Iba fun eledua
Aho ha ha aho
Mo wo le mo boluwa mi so ro
Ninu ikpon ju
Ninu I damu
Be bi ban kpo na
Ma wo le ma boluwa mi soro
Pe mi o le yan
Baye ba foju dimi
Pe mi o ni le
Ma wo le ma boluwa mi soro
Aho ha ha a ho, aho
Iba fun eledua
Aho ha ha aho
Ma wo le ma boluwa mi soro
Ninu ikpon ju
Ninu I damu
Be bi ban kpo na
Ma wo le mo boluwa mi soro
Mo o ni foju sunku mo o o o
Aye lo ja, orun ni ile
ẹni a fi ba mi
Iba O O O



Writer(s): Cobhams Emmanuel Asuquo, Bukola Elemide


Asa - ASA (Asha) [Deluxe Edition]
Album ASA (Asha) [Deluxe Edition]
date de sortie
20-10-2008




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.