Asa - Awe paroles de chanson

paroles de chanson Awe - Asa



Awe I bo lo lo ka
Ta n fi wao ka
Ibi o ba lo je a mo
Anti to n gbe le I to si
O wa o wa le yi
Ati o jo meta atabo
O wi kpe o, o
O loyun fun o
Oyun oshu meji
Oloyun fun o
Ani yipe o
O loyun fun o
Iwo iwo nah
O loyun fun o
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Anti to loyun fun o
O to bi o l'omo
Iwo iwo na
Anti to loyun fun o
Ani o to bi e l'omo
Iwo iwo na
O bi 'mo oh oh
O bi 'mo
O bi 'mo oh oh
Omo so layo
Ire lo ni mu, ese, irun ori
Iwo dudu omo kpu pa
Ba wo lo se ri
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Wahidi omo sekina
Omo muyina
Omo mohammed
Ha ha haaa
Haaaaa aaaaaa
Ewa wo ja la a fin oba ejigbo ha
Atabo, atako wan ja la fin oba la fin oba o
Haaaa haha
Haaaa haaaaa haaaa
Wahidi omo muyina ni
Omo sekina
O foju mi ri mabo
Mabo ni le, mabo loko mabo l'eko
Mama to bi mama re ni mama mi
Emi na bi te mi, bi te mi
Moo ntomo lowo f'omo loyon
Ma ko tire bami bami
Haaaa oohh
Abo oro lan so f'omo Luabi
To ba de nu re a do n di n di
Din din



Writer(s): Bukola Asa Elemide, Asuquo Cobhams


Asa - Asa
Album Asa
date de sortie
09-08-2008




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.