Asa - Eye Adaba (Unreleased Version) paroles de chanson

paroles de chanson Eye Adaba (Unreleased Version) - Asa




Oju mo ti mo
Oju mo ti mo mi
Ni le yi o o
Oju mo ti mo - mo ri re o
Oju mo ti mo
Oju mo ti mo mi
Ni le yi o o
Oju mo ti mo - mo ri re o
Eye adaba
Eye adaba
Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
Wa ba le mi o o
Oju mo ti mo mo ri re o
Eye adaba
Eye adaba
Eye adaba ti n fo lo ke lo ke
Wa ba le mi o o
Oju mo ti mo mo ri re o



Writer(s): Asa, Cobhams Asuquo



Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.