Asa - Ilu paroles de chanson

paroles de chanson Ilu - Asa



Ti ilu o ba dun
Ti ilu o ba dun at all
Ti ilu o ba dun
Eyin le mo be se se
Ti ilu oba dun
Ti ilu oba dun at all
Ti ilu oba dun
Eyin le mo be se se
I remember long time ago
I remember laye ati ijo
Bomu shile kan lofi ra onje si ile
Baba aje yeyeaje pmo aje ti yo
Onje aje ju
Onje aje wobi
Onje aje yi
Amo nisi nisinisi
Gari tiwon epa ti tan
Sibi ile wa gbolude
Ti ilu oba dun
Ti ilu oba toro at all
Ti ilu oba dun
Eyin le mo be sese
There was once a time
Dollar je naira lowo
There was once a time a jeun lati ara cocoa
There was once a time mo re ilu oyinbo sere
Mo sere lo mo sere bo
Kosi wetin you carry
Ah ah
Moje aje bi
Moje aje wobi
Moje aje yi
Moje se sere
Amo nisi nisinisi
Ilu oda ole nja
Naira lowa je dollar lowo
Ti ilu oba dun
Ti ilu oba toro at all
Ti ilu oba dun
Eyin le mo besese
Oh oh
Ti ilu oba dun ti ilu oba toro at all
Ti ilu oba dun
Eyin le mo besese



Writer(s): Copyright Control


Asa - The Captivator
Album The Captivator
date de sortie
19-01-2014




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.