paroles de chanson Ọlánrewájú - Brymo
Igba
o
lọ
bi
orere
Bo
ba
koro,
oṣi
maa
dun
ah
Eni
to
ni
suuru,
kii
ṣeyan
kekere
Bo
ba
kan
lẹ,
oṣi
maa
goke
ah
Boo
ba
ṣe
un
tọ
fe,
won
maa
kẹyin
si
e
(ẹh
a
ẹh)
Bo
ba
ṣe
tirẹ
o,
o
ma
jẹ
ire
fun
ẹ
(ẹh
a
ẹh)
Ọlanrewaju
ọmọ
ọba
E
ma
suure
da
gba,
won
ni
ko
o
ṣe
were,
roora
ṣe
E
ma
suure
da
gba
oo
Olooto
ko
ni
ku
si
bi
ọtẹ
ooo
Olanrewaju
ọmọ
mi,
e
ma
suure
da
gba
oo
Igba
o
lọ
bi
orere
Bọmọde
oku
oo,
oṣi
maa
da
gba
Ṣọra
funja,
ṣọ
ra
fẹgbẹkẹgbẹ
Oun
tio
to
o,
oṣi
maa
pọ
da
nu
Gbogbo
eni
abi
lo
ma
ku,
eh
Eh
a
ẹh
Iwa
ta
a
wu
lo
ma
ku
(ẹh
a
ẹh)
Ọlanrewaju
ọmọ
oba,
e
ma
suure
da
gba
o
Won
ni
ko
ṣe
were,
roora
ṣe
E
ma
suure
da
gba
oo
Olooto
ko
ni
ku
sibi
ọtẹ
oo
Ọlanrewaju
ọmọ
mi,
e
ma
suure
da
gba
o
Olooto
ko
ni
ku
sipo
ika
oo
Olooto
ko
ni
ku
sibi
ote
oo
Ọlanrewaju
ọmọ
ọba,
ee
ma
suure
dagba
oo
Ọlanrewaju
ọmọ
mi,
ee
ma
suure
da
gba
oo

1 No Be Me
2 Mama
3 Heya!
4 Patience and Goodluck
5 God Is in Your Mind
6 Time Is so Kind
7 Entropy
8 Money Launderers and Heart Breakers
9 Ọlánrewájú
10 Olúmọ
11 Bá’núsọ
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.