Efe Nathan - Jesu Seun paroles de chanson

paroles de chanson Jesu Seun - Efe Nathan



Iye iye
Olori aye oooo mo ki ooo
Iye iye
Aah e Jesu seun
O f'ami ororo yan mi
Oni ma foya/2x
Nwo korin ogo re titi lailai/4x
Verse 2: elerun niyin
Oba awi maaye 'hun
Gbongbo 'dile jese aterere kari aye
Eyin lope ye, eyin niyin ye oo
Dansaki re olu olorun oba mi mokio oo
Aah ee...
Verse 3: mo wo kari aye boya emi o ri oba bi re o, laye at'orun koma seni keni bi re oo baba, oba ti ki'n doju tini asoro matase, emi o gbeoga nko korin ogo re titi lailailailailailailai
Aaah ee
Bridge: ooooolori aye oooo, oba ti n fi imole s'aso 'bora, kaabiesi
Call: Jesu seun
Resp. Jesu seun/3x
Call: olugbala seun
Resp: Jesu seun
Call: eledami seun
Resp. iba feledumare oba
Call: Olorun mi seun seun oo
Resp. iba feledumare oba
Call: eledumare oseun
Resp. iba feledumare oba
Call: olorun mi seun seun ooo
Resp. iba feledumare oba
Jesu seun iba f'eledumare oba...



Writer(s): Akinwunmi Oluniyi Akiremi, Efe Peace Nathan


Efe Nathan - Broken
Album Broken
date de sortie
04-08-2014




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.