King Sunny Ade - Ekilo Fomo Ode - traduction des paroles en anglais

Paroles et traduction King Sunny Ade - Ekilo Fomo Ode




Ekilo Fomo Ode
Ode to the Hunter's Child
Awo re gungun lobirin le ṣe
My love, like a chameleon, is hidden
Awo gẹlẹdẹ lobirin le mọ
My love, like a masked dancer, is known
Bi obinrin fi oju doro, oro a gbe
When a woman is beautiful, people will talk
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ode to the hunter's child, come home soon
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ode to the hunter's child, come home soon
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Come back and accept what is rightfully yours
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Obedience is better than offering expensive sacrifices
Konko jabẹlẹ
The horn of destiny
Kaluku l'omi se ti é
Everyone determines their own fate
Konko jabẹlẹ
The horn of destiny
Kaluku l'omi se ti e
Everyone determines their own fate
Konko jabẹlẹ
The horn of destiny
Kaluku l'omi se ti e
Everyone determines their own fate
Konko jabẹlẹ
The horn of destiny
Kaluku l'omi se ti e
Everyone determines their own fate
Ki àwon ṣe tiwọn
Let them do what they do
Ki ẹyin ṣe t'ẹyin
Let you do what you do
Ki àwa ṣe t'awa
Let us do what we do
Konko jabẹlẹ
The horn of destiny
Kaluku l'omi se ti e
Everyone determines their own fate
Amò ṣá
Amen
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ode to the hunter's child, come home soon
Ékilo f'ọmọ odẹ, koma rìnrìn pado
Ode to the hunter's child, come home soon
Koma sesi fara ko odidan lojiji
Come back and accept what is rightfully yours
Ìgbọràn sàn ju ẹbọ riru
Obedience is better than offering expensive sacrifices





Writer(s): King Sunny Adé


Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.