King Sunny Ade - Kosun Tadie paroles de chanson

paroles de chanson Kosun Tadie - King Sunny Ade



Wan ran ′mọ lọ'ja
Ko lo r′ori ọkà oni nọyin wa
Wan ran 'mọ lọ'ja
Ko lo r′ori ọkà oni nọyin wa
Itun meje, at′arẹ meje pẹlu adere meje
Wan wa gun pọ, wan ko m'ọṣẹ dudu
Wan wa gbefun padi
Padi Ọdẹnson
Wan wa gbefun padi
(Padi Ọdẹnson)
Wan wa gbefun padi
(Padi Ọdẹnson)
Oṣika ma ṣe′ka mọ o
(Ika a p'oni′ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p′oni'ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p′oni′ka o)
Oṣika ma ṣe'ka mọ o
(Ika a p′oni'ka o)
Ika a p′oni'ka o
(Ika a p′oni'ka o)
Ika a p'oni′ka o
(Rere a b′ẹni rere)
Ika a p'oni′ka o (hee)
(Rere a b'ẹni rere)
Odaju
Ẹni gbẹkun gba laye
Aya rẹ a jẹ, ọmọ rẹ a jẹ
Oun naa a wẹwẹ sẹ



Writer(s): King Sunny Adé


King Sunny Ade - Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.