King Sunny Ade - Nitori Awa paroles de chanson

paroles de chanson Nitori Awa - King Sunny Ade



Wan lọ gb'ẹbọ ni oríta mẹta
Nitori awa
Wan ko jẹ ki babalawo ko simi lalẹ
Nitori awa
Wan ba kuro ni shọshi wan gba'le ra daun shelọ
Nitori awa
Eku ina'wo ẹran pipa l'ojo jumọ
Nitori awa
Wan ma gb'ẹbọ wan ni ihoho lo gan jọ oru
Nitori awa
T'aba wi tan wan ma gbe bíbélì ọrọ kiri
Nitori awa
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
ma wulẹ sáré ka
Kuru kẹrẹ, o di 'le alawo
Kuru kẹrẹ
Kuru kẹrẹ, o di 'le oniṣegun
Ogun o ran wa o
ma wulẹ sáré ka



Writer(s): King Sunny Ade


King Sunny Ade - Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward
Album Classics, Vol. 2: Ekilo Fomo Ode & the Way Forward
date de sortie
27-11-2001




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.