paroles de chanson Soapy - Naira Marley
O
t'ẹsẹ'le
bọ
Yahoo
ni
babalawo
(Yahoo
ni
babalawo)
Ole
l'everybody
Ẹni
ilẹ
mọ
ba
ṣa
ni
barawo
(Barawo,
barawo,
barawo)
(Mọ
ba
ṣa
ni
barawo)
O
tẹsẹ'le
bọ
(O
tẹsẹ'le
bọ)
Yahoo
ni
babalawo
(Yahoo
ni
babalawo)
Ole
l'everybody
Ẹni
ilẹ
mọ
ba
ṣa
ni
barawo
O
fẹ
ṣe'ka
fun
mi
(O
fẹ
ṣe'ka
fun
mi)
Mi
o
l'ogun
mo
ni
Kurani
(mo
ni
Kurani)
Mo
dẹ
n
ṣ'adura
mi
Bi
m
ṣe
n
ṣ'adura
mi
Allah
n
gba'dura
mi
(Allah
n
gba'dura
mi)
A
ti
lọ
a
ti
de
(A
ti
lọ
a
ti
de)
Ẹni
ori
yọ
o
di'le
(Ẹni
ori
yọ
o
di'le)
Ẹni
ba
lọ
l'o
ba
de
Igba
ti
m
pada
de
N'ṣe
l'ọn
de
mi
l'ade
(N'ṣe
l'ọn
de
mi
l'ade)
K'ade
ko
pẹ
l'ori
(K'ade
ko
pẹ
l'ori)
Ki
bata
k'o
pe
l'ẹsẹ
(Ki
bata
k'o
pe
l'ẹsẹ)
K'awọn
ọta
mi
kan
l'ẹsẹ
Inside
life
(Inside)
O
ti
ri
5 Alive
(O
ti
ri
5 Alive)
Inside
life
(Inside)
O
ti
ri
Deeper
Life
(O
ti
ri
Deeper
Life)
Inside
life
Awọn
kan
n
jẹ'ya
Awọn
kan
n
chop
life
(Inside
life)
Inside
life
Awọn
kan
n
ṣ'epe
Awọn
kan
n
jẹ'wa
Jo
soapy,
soapy
Kirikiri
n
jo
soapy
(Kirikiri
n
jo
soapy)
Jo
soapy,
soapy
Ikoyi
prison
n
jo
soapy
(Ikoyi
prison
n
jo
soapy)
Jo
soapy
Ninu
cell
EFCC
wọn
n
jo
soapy
(wọn
n
jo
soapy)
Jo
soapy
T'o
o
ba
ni'yawo
n'le
k'o
jo
soapy
(Soapy!)
soapy,
soapy
Bọda
yi
n
jo
soapy
(Bọda
yi
n
jo
soapy)
Soapy
(Soapy)
Ab'ẹyin
naa
soapy?
(Ab'ẹyin
naa
soapy?)
Soapy
(Soapy)
Single
father
n
jo
soapy
(Single
father
n
jo
soapy)
Soapy,
ma
lọ
lo
OMO
t'o
ba
lọ
n
soapy
(Soapy!)
Ṣ'o
d'owo
mọ?
(Ṣ'o
d'owo
mọ?)
O
wa
sọ
p'o
o
mọ
Naira
(O
wa
sọ
p'o
o
mọ
Naira)
O
wuwo
l'ọwọ
Iwọ
ṣaa
ṣẹ
si
Naira
(Iwọ
ṣaa
ṣẹ
si
Naira)
Aja
fẹ
de'na
d'ẹkun
Kekere
ẹkun
o
ma
n
s'ẹgbẹ
aja
(ko
n
ṣ'ẹgbẹ
aja)
Wọn
n
bẹ
ni,
Ma
fọ
Awọn
naa
o
fẹ
wahala
(Awọn
naa
o
fẹ
wahala)
I
just
wanna
make
Mama
proud
(I
just
wanna
make
Mama
proud)
They
want
to
make
Mama
cry
Mama
you
gonna
cry
no
more
T'ẹ
ba
sun'kun
gan
ẹ
o
sọ'kun
ayọ
(ẹ
o
sọ'kun
ayọ)
Ti
m
ba
n
jo
k'ẹ
ba
m
yọ
(k'ẹ
ba
m
yọ)
K'ọrọ
mi
ja
s'ayọ
(K'ọrọ
mi
ja
s'ayọ)
Inside
life,
Inside
life
Do
a
one
course,
it's
my
life
(Ku'onbẹ!)
Inside
life
(Inside)
O
ti
ri
5 Alive
(O
ti
ri
5 Alive)
Inside
life
(Inside)
O
ti
ri
Deeper
Life
(O
ti
ri
Deeper
Life)
Inside
life
Awọn
kan
n
jẹ'ya
Awọn
kan
n
chop
life
(Inside
life)
Inside
life
Awọn
kan
n
ṣ'epe
Awọn
kan
n
jẹ'wa
Jo
soapy,
soapy
Kirikiri
n
jo
soapy
(Kirikiri
n
jo
soapy)
Jo
soapy,
soapy
Ikoyi
prison
n
jo
soapy
(Ikoyi
prison
n
jo
soapy)
Jo
soapy
Ninu
cell
EFCC
wọn
n
jo
soapy
(wọn
n
jo
soapy)
Jo
soapy
T'o
o
ba
ni'yawo
n'le
k'o
jo
soapy
(Soapy!)
soapy,
soapy
Bọda
yi
n
jo
soapy
(Bọda
yi
n
jo
soapy)
Soapy
(Soapy)
Ab'ẹyin
naa
soapy?
(Ab'ẹyin
naa
soapy?)
Soapy
(Soapy)
Single
father
n
jo
soapy
(Single
father
n
jo
soapy)
Soapy,
ma
lọ
lo
OMO
t'o
ba
lọ
n
soapy
(Soapy!)
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.