paroles de chanson Ojo Ayo - Oriyomi Kehinde
Eni
timofe
denu
adun
aye
mi
ni
Eni
timo
fo
fun
timo
gbafun
ife
mi
ni
Ololufe
mi
timo
yan
gege
bi
ishan
ara
Timo
ba
nbinu,
timo
ba
nbinu
Timo
ba
nbinu
tonbemi
tinba
sope
rara
Eyin
e
kanlo
bami
wa
ololufemi
lo
Okan
toti
gbona
atutu
lalai
b'omi
si
Iwo
nimofe
pe
koma
se'toju
mi
ni
Modupe
p'awon
obi
e
gba,
won
o
sope
rara
Bose
nsemi
gan
mio
leso,
Olohun
shaloye
Ololufemi
afiwo
naa
lotunye
Bi
adanwo
ni
oro
ife
toladun
bi
oyin,
t'aba
ti
renikeji
tonfeni
denu
Jerryson
production
Moyan
ifemi
nibi
totida
Mio
kabamo
pemose
l'aya
Olohun
loni
kinpe
e
lojoyen
o,
modupe
Olohun
motun
t'opeda
Moyan
ifemi
nibi
totida
Mio
kabamo
pemose
l'aya
Olohun
loni
kinpe
e
lojoyen
o,
modupe
Olohun
motun
t'opeda
MashaAllah
Moyan
ifemi
nibi
to
tidun
o
Mio
kabamo
pemose
loko
Olohun
loni
kingba
lati
fe
e
o,
modupe
Olohun
motun
t'opeda
Moyan
ifemi
nibi
to
tidun
o
Mio
kabamo
pemose
loko
Olohun
loni
kingba
lati
fe
e
o,
modupe
Olohun
motun
topeda
Miio
shife
mo
r'olooto
momu
Mio
shiyan
mo
fenikeji
s'aya
Mo
nigbagbo
pewo
sha
layan
funmi
o,
kajo
mawa
ni
dojo
ale
ayami
Moyan
ifemi
nibi
totida
Mio
kabamo
pemose
l'aya
Olohun
loni
kinpe
e
lojoyen
o,
modupe
Olohun
motun
t'opeda
Mio
f'àlè
soko
mo
r'olooto
fisoko
Mio
siyemeji
kinto
ba
e
lo
mogba
Pewo
gangan
leni
ti
a
yan
momi
o,
taojo
gbepo
dojo
ale
okomi
Moyan
ifemi
nibi
to
tidun
o
Mio
kabamo
pemose
loko
Olohun
loni
kingba
lati
fe
e
o,
modupe
Olohun
motun
t'opeda
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni,
igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni,
igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Sebi
nigba
ti
e
rirayin
sebi
enikan
soso
Lokoko
so
fenikeji
pe
jekadi
ife
ara?
Iyawo
lokoko
sako
oloun
o
gba
o
Oko
e
oje
ko
sinmi
otun
gbiyanju
o
Pomo
totutu
niwa
lojo,
sowa
gbodo
loni?
Yoruba
ni
koje
ngbadun
lobinrin
ngbafun
Oun
gangan
niyawo
e
fiwa
pada
gba
o
Toko
tiyawo
alarede
ti
d'oloruka
o
E
jeka
fayo
bawon
dupe
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni
Igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Oko
iyawo
tiso
funmi
o
l'oriyomi
o
Monife
iyawo
mi
denu
o
koja
wasa
o
O
l'egbin
nimo
lefiwe
boje
t'ewa
ni
O
l'adàbà
lale
fiwe
boje
t'iwa
ni
O
lodabi
oju
lara
tio
gbodo
fo
O
lodabi
aso
lara
tio
gbodo
ya
ni
O
loun
maloje
koun
mo
adun
ife
o
Loje
koun
fi
sepinnu
poun
gbodo
fe
Ni
tako
tabo
alarede
ba
doloruka
o
Toko
tiyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni
Igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Iyawo
matiso
boseri
lara
oun
gangan
Iyawo
matiso
boseri
lara
oun
O
loko
timofe
wumi
modupe
oni
o
O
leni
bi
okan
mi
o
koja
okunrin
Tenikan
leri
ta
gboju
wipoun
o
ri
Ajanaku
koja
kokoja
ka
laomo
Iduro
e
ni
kaso
ni
abi
t'ewa
ni
Abi
t'iwa
t'okunrin
fi
nsike
aya
O
loun
gan
time
ipinnnu
poun
gbodo
fe
T'oko
tiyawo
alarede
ba
doloruka
o,
eje
kafayo
bawon
mujo
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni
Igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
MashaAllah
Olohun
ti
soyin
papo
kema
pada
ja
Olohun
to
seyin
lokan
niko
fadunsi
Oba
toseyin
lolufe
emi
ikorira
Koni
gbajoba
ife
yin
allahumma
amin
Koni
koro
titi
laye
ife
adun
bi
oyin
ni
K'ifedayo
ke
dolope
keyin
masepada
dota
Oni
o
mani
kolofin
ojo
ayo
ni
Igbeyawo
alarinrin
lawase
loni
o
T'oko
t'iyawo
alarede
ti
d'oloruka
adupe
Yah
robbi
maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Yah
robbi
maje
kiwon
tuka
o
Allah
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
ma
delesinrin
amin
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Yah
robbi
maje
kiwon
suffer
o
Allah
Mase
fiya
dan
won
wo
lailai
Ilahi
ma
yawon
lagan
amin
o
K'esu
masiwon
lona
Allah
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
ma
doniranu
amin
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Iyawo
ojo
oni
o
Allah
Iyawo
ojo
oni
o
Allah
Maje
koso
foko
e
po
tan
Ibagbe
ibasepo
ola
Maje
ko
diso'nu
eku
Allah
Amumora
toba
lefa
ironu
o
Maje
kiyen
osele
Amin
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
K'igbeyawo
alarinrin
ma
doniranu
titi
lai
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Olohun,
agbara
toko
o
malo
fise
Agbara
toko
yio
malo
fise
Olohun
mafi
won
oko
e
amin
Maje
kogba
alagbase
oru
Oro
toko
o
malo
ba
fun
Maje
k'oko
o
d'otubante
o
Ola
tio
fi
kebi
e
ba
nfun
Biwon
sefe
bere
aye
tuntun
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
ma
delesinrin,
koma
doniranu
lailai
Maje
kiwon
tuka
o
Allah
Toko
tiyawo
oloruka
ti
dikanna
o
Biwon
sewa
bere
aye
tuntun
o
ife
Igbeyawo
alarinrin
maje
kodija
lailai
Alubarika
ibe
mafi
dunwa
karowo
na
Ebun
ibe
mafi
dunwa
karomo
bi
o
Omo
abiro
abiye
tako
tabo
Alubarika
ibe
mafi
dunwa
karowo
na
Ebun
ibe
mafi
dunwa
karomo
bi
o
Omo
abiro
abiye
tako
tabo
Terin
tayo
lafi
pade
ta
finyo
Isoro
ibe
mafi
kanwa
kama
sunkun
o
Ka
bawon
gbe'beji
abiro
takotabo
Alubarika
ibe
mafi
dunwa
karowo
na
Ebun
ibe
mafi
dunwa
karomo
bi
o
Omo
abiro
abiye
tako
tabo
Ki
toko
taya
mapada
gbera
sepe
Ife
tobere
ni
konmalo
dojo
ale
won
Irepo
lafe
kosele
titi
lai
Alubarika
ibe
mafi
dunwa
karowo
na
Ebun
ibe
mafi
dunwa
karomo
bi
o,
omo
abiro
abiye
tako
tabo
Iyawo
ti
roko
gbamu
o
adupe
o
O
l'abelejayan
kewabi
joko
si
Oko
ti
riyawo
e
dimu
o
adupe
o
O
l'abelejayan
kewabi
joko
si
Gbogbo
Eni
towa
akiyin
emama
seun
Ao
firu
e
gba
pelode
idunnu
Baba
oko
nkinyin
pema
mase
o
Ao
firu
e
gba
pelode
idunnu
Mama
oko
nkiyin
pema
mase
ee
Ao
firu
e
gba
pelode
idunnu

Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.