paroles de chanson Adake Dajo - Tope Alabi
Adake
dajo
On
lo
mo
wa
o,
O
mi
wo
wa
w'okan
Ohun
gbogbo
ti
a
gb'aye
se
On
lo
da
ojiji
mo
wa
o
Ipilese
aye
wa
ooo,
at'opin
re,
O
ri
gbogbo
koro
Adake
dajo
On
lo
mo
wa
o,
O
n
wo
wa
w'okan
Ohun
gbogbo
ti
a
gb'aye
se
On
lo
da
ojiji
mo
wa
Ipilese
aye
wa
ooo,
at'opin
re,
O
ri
gbogbo
koro
Eni
to
da
oju
o,
ko
ni
s'alairiran
Olu
to
da
eti
o,
ko
le
s'alaigboran
Ko
si
koro
loju
Re,
gbangba
kedere
lo
ri
gbogbo
wa
Adake
dajo
On
lo
mo
wa
o,
O
n
wo
wa
w'okan
Ohun
gbogbo
ti
a
gb'aye
se
On
lo
da
ojiji
mo
wa
Ipilese
aye
wa
ooo,
at'opin
re,
O
ri
gbogbo
koro
K'a
ye
s'esin,
k'a
ye
pe
e
ni
esin,
k'a
lo
ja'wo
pata
A
o
le
gan
Olorun
pelu
'gbagbo
oju
tori
ko
ni
le
gba
wa
A
n
fi
ti'pa
gboran
si
'lana
esin,
ofin
Olorun
wa
d'afieyin
Opo
dara
loju,
iwa
won
o
dokan
T'egbin
t'idoti
ko
je
k'adura
opo
onigbagbo
o
gba
Ojiji
t'Eleda
da
mo
wa,
o
n
s'afihan
ohun
ikoko
o
E
o
ni
le
gba'bode
f'Olorun,
onitohun
a
wule
tan
'ra
e
pa
Olorun
alawopa,
dakun
ma
wo
mi
pa
Adake
dajo
On
lo
mo
wa
o,
O
n
wo
wa
w'okan
Ohun
gbogbo
ti
a
gb'aye
se
On
lo
da
ojiji
mo
wa
Ipilese
aye
wa
ooo,
at'opin
re,
O
ri
gbogbo
koro
Eemo
to
wo
'jo
Olorun
ti
wa
bureke,
gbogbo
aye
di
'ranse
Olorun
At'eni
Baba
ran,
at'eni
ebi
le
de
Woli
osan
gangan,
iyen
lo
bi
rere
Ori
pepe
di
'gbale
egungun
At'alafose
at'elepe
Ogo
ologo
de
ku
t'on
mi
wo
s'agbara
Igbadi
m
be
labe
collar
opo
won
Awon
t'ogun
nja
t'on
tori
k'ogun
o
le
se
t'on
wo
'nu
ijo
wa
O
ma
se
arakun
laso
gbagi
logun
to
n
kun
ogun
won
Ab'e
o
ri
ijo,
ki
Jesu
to
de
ki
ni
yio
da
o
Adake
dajo
On
lo
mo
wa
o,
O
n
wo
wa
w'okan
Ohun
gbogbo
ti
a
gb'aye
se
On
lo
da
ojiji
mo
wa
Ipilese
aye
wa
ooo,
at'opin
re,
O
ri
gbogbo
koro
E
je
k'a
bi
'ra
wa
leere,
gbogbo
iranse
Olorun
pata
Kini
idahun
si
ibeere
yi
o
Oro
ijoba
orun
ti
di
'waasu
igbaani
lenu
wa
Ere
wo
lonisowo
agba
n
je
ninu
ise
wa
E
gbo
ere
wo,
ere
wo,
lOluwa
n
je
A
fowoleran
O
ma
n
wo
wa
o
Ko
ma
ka
'se
mi
lai
lere
kankan
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Nigba
t'a
ba
p'oruko
awon
eniyan
Ta
o
ba
pe
omo
omo
o
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Nigba
t'a
ba
p'oruko
awon
eniyan
Ta
o
ba
pe
omo
omo
o
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
T'a
ba
p'oruko
ni'joba
orun
T'a
pe
won
titi
ti
o
de
kan
e
o
Eni
to
n
toka
s'omo
apaadi,
at'eyin
to
mo
'mo
ile
ologo
T'on
ba
p'oruko
ni'joba
orun,
t'on
o
ka
mr
census
e
ki
loo
ro
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Nigba
t'a
ba
p'oruko
awon
eniyan
Ta
o
ba
pe
omo
omo
o
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Onigbagbo
ka
ri
mi
ete
eke
Lati
inu
ijo
je
'ra
wa
lese
dede
Adura
at'aawe
odi
s'enikeji
Ife
ikoko
lori
pepe
si
pepe
E
o
ranti
O
da
ogbon
o
ju
ogbon
lo
E
o
ba
lako
bi
ibon
lese-o-gbeji
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Nigba
t'a
ba
p'oruko
awon
eniyan
Ta
o
ba
pe
omo
omo
o
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Ojo
nla,
Adajo
aye
fere
de
Aiyiwapada
idajo
a
ro
K'onikaluku
lo
ye
'ra
e
wo
Ibi
t'o
ba
ku
si,
gb'adura
k'o
tun
se
Ko
ma
ba
di
ki
loo
ro
K'enu
ma
wo
ji,
ailesoro
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Nigba
t'a
ba
p'oruko
awon
eniyan
Ta
o
ba
pe
omo
omo
o
Ki
loo
ro,
ki
loo
so
Eh
eh
eh
eh
eh
eh
mo
wi
t'emi
o,
ore
ma
di'ti
Ko
ma
di'na
orun
mo
'ra
e,
o
ti
n
f'ami
han,
Jesu
o
ni
pe
de
Eru
igi
to
n
be
loju
re,
lo
gbe
kuro,
ko
ye
tenubole
soro
Lo
ronu
ko
pa
iwa
da,
ka
si
toro
fun
aanu
K'a
ju'wo
ju'se
k'a
tuba
f'Olorun,
K'a
le
ba
joba,
k:
a
le
ka
wa
mo
won
Ise
wa
laye
yi
ni
lati
wa
ijoba
Olorun
Leyin
re,
ohun
to
ku,
a
o
fi
fun
wa
O
n
bo
laipe,
s'asaro
aye
re
Ise
wa
laye
yi
ni
lati
wa
ijoba
Olorun
Leyin
re,
ohun
to
ku,
a
o
fi
fun
wa
O
n
bo
laipe,
s'asaro
aye
re
Ise
wa
laye
yi
ni
lati
wa
ijoba
Olorun
Leyin
re,
ohun
to
ku,
a
o
fi
fun
wa
O
n
bo
laipe,
s'asaro
aye
re
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.