Tope Alabi - Alagbara paroles de chanson

paroles de chanson Alagbara - Tope Alabi



Alagbara aye
Aye a tan ooo
Eni loni egbo
Awon to shana
Won o si moo
Igba loni igba nlo
Bawo lo si ire
Yo san esan
Olojo die laye
Ma gba ona kan kan
Ofefe laye asan
Maje ko wo e leje
Igba o lo bi orere
O f'ogun odun sebi
Yio fa da gbaro
Ke ya lomo pe otipa
Ida pani yio ti'da ku o



Writer(s): Patricia Temitope Alabi


Tope Alabi - Alagbara
Album Alagbara
date de sortie
17-08-2012




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.