paroles de chanson Kape Laye - Tope Alabi
Kaape
laye
Ka
lo
Ile
aye
titi
Ko
ni
Kaye
gbo
ooooooo
Aye
lole
lo
niyan
keee
gbo
Igba
ta
gbe
laye
Ohun
a
gbe
Ile
aye
she
gbogbo
Keledua
je
kaa
le
pitan
rere
Omi
aye
to
ru
siwa
seyin
o
Awon
kan
gbaye
Won
pitan
iṣẹ
titi
Wọn
pitan
ìṣòro
kolopin
rárá
Ọrọ
wọn
o
Papa
jasayo
o'mase
O'jojo
aye
ni
won
fojú
sògbérè
ẹkun
Titi
ikú
fi
p'awọn
won
o
lenu
dupẹ
Omi
aye
to
ru
siwa
seyin
ooo
Awọn
kan
gb'ayé
wọn
jadun
ayé
Títí
won
gbàgbé
asèdá
t'oda
ayé
Ọrọ'
ayé
rú
bo
wọn
lójú
jọjọ
alumoni
Wọn
l'ayé
wọn
f'ogo
rẹ
fún
satani
nii
Igbagbe
ṣewọn
pé
òun
gbogbo
tọwọ
asèdá
wa
o'mase
o'mase
Òun
gbogbo
toni
kaluku
ní
wọn
fi
fesu
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.