paroles de chanson Oba Aseda - Tope Alabi
A
toto
n
to
Olodumare,
Olorun
ogo,
Iba
Re,
Iba
o,
Akoda
aye,
Iwo
nikan
lo
to,
iba!
A
de'da,
a
m'eda
Oba
Alamo
to
mo
'ponri
eda
o
Akoko
orun
on
aye
Opo
kan
a
gbamu
aye
o
Ogo
ni
mo
wa
yin
o
o
Oba
Kabiyesi
Re,
Olorun
toto
Ogo,
yeeee,
ogo
Akoko
ade
Iwo
loba
Omimi
aye
ti
o
le
mi
lailai
o
Olu
inu
awon
orun
Asaya
apesin
asako
Iwo
to
tobi
ju
o
lorun
O
f'aye
s'apoti
itise
lasan
Ogo,
yeeee,
ogo
Ogo
ye
o,
yeeeee
ogo
Olorun
agbaye,
mo
f'ogo
fun
O
ooo
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Iwo
lajulo
ti
o
see
julo,
mo
f'ogo
fun
O
Baba
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Atetekose
Adiitu
Oro,
mo
f'ogo
fun
O
Baba
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Alapanla
to
so'le
aye
ro,
mo
f'ogo
fun
O
ooo
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Iwo
ni
'gunwa
ogo
ti
o
lafiwe,
mo
f'ogo
fun
O
Oba
nla
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Awari
Re
aimo
ni
f'aye
at'orun
Ipa
o
to
ju
gbogbo
ipa
lo
Angeli
o
le
s'akawe
ogo
Re
Didan
ninu
ewa
at'orun
d'orun
O
da'ye
k'ohunkohun
to
d'aye
Akoko
k'angeli
orun
to
wa
Iwo
to
n
s'ohun
to
tobi
ju
awari
lo
Owo
ogo
to
f'ara
s'ohun
gbogbo
logo
Ogo
yeeeee
ogo
Iba
o,
yeeeee
iba
o
Iba
Re
Olorun
o,
Oba
ayeraye
e
Kabiyesi
Re
o,
Iwo
nikan
lola
ododo
to
si
Mo
wa
juba
Re
o,
Iwo
nikan
lola
ododo
to
si
o
Olorun
agbaye,
mo
f'ogo
fun
O
ooo
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Erujeje
Arugbo
Ojo,
Agba
lailai
on
lo
je
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Olurapada
wa,
Ododo
to
n
tan
'mole
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Oba
t'aa
bi,
sugbon
ti
a
ko
da
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Ilekun
to
ti
mo
iku,
Kokoro
si
iye
ayeraye
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
You
are
the
Might
above
all
mights
Angels
count
Your
glory,
incomparable
Shining
in
beauty
from
heaven
to
heaven,
Creator
of
eternal
things
You
are
the
first,
before
the
heavenly
angels
You
bigger
than
searchable
Glorious
and
stylishly
working
all
glory
Glory
Oh
Glory
(Ogo
ogo)
Unquestionable
Great
King,
be
Thou
glorified
Daddy
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Awon
angeli
juba
Re,
lojoojo
o
lorun
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Embodiment
of
wisdom
and
power
You
are
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Agbaagba
lorun
juba
Re,
won
fi'ba
yi
O
ka
Baba
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Worker
of
numerous
wonders,
worshipped
in
trembling
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Gbogbo
aye
mi
ni
mo
fi
juba
Re,
gba
ogo
lori
mi
o
Baba
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
You
are
the
King
Creator,
be
Thou
glorified
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Ola
ododo
lo
to
si
'Wo
nikan
nikan
o
Iwo
loba
Aseda,
mo
f'ogo
fun
O
Iba
Re
Olorun
o,
Oba
ayeraye
e
Kabiyesi
Re
o,
Iwo
nikan
lola
ododo
to
si
Mo
wa
juba
Re
o,
Iwo
nikan
lola
ododo
to
si
o
1 Oba Aseda
2 Odara Ni Ife
3 Oruko Oluwa
4 Oruko Tuntun
5 Mo Mope Mi Wa
6 Ikoko Oga Ogo
7 Aye Yii
8 Oro Kan Soso
9 Tipa Tikuuku
Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.