9ice - Mo Gbese Le текст песни

Текст песни Mo Gbese Le - 9ice



Alápò meji (ye)
Milẹ
(Mo gbẹsẹ le, mo gbẹsẹ le, mo gbẹsẹ le o)
(Mo gbẹsẹ le, mo gbẹsẹ le, mo gbẹsẹ le o)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
Omọ yẹn ba ṣe di rogodo (Omọ yẹn ba ṣe di rẹbẹtẹ)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
O bembe, o bembe, ye (o bembe, o bembe)
Ọba gba, ọba gba
Lori ohun gbogbo, gbogbo
Ọba gba, ọba gba
Lori ohun gbogbo, gbogbo
Eyi ga, eyi ga
Hang e ninu sokoto
Eyi ga, eyi gẹ
Fine girl ninu sokoto
See, see, see, see them dey dance oh
See, see, see them dey dance oh
See the way them dey roll oh
See the way them dey roll oh
Mo lo gbagidi, gbagidi, o pa kaja
O gba gidi, o pa kaja
O gba gidi, o pa kaja
Ọmọde yi, O gba gidi, o pa kaja
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
Omọ yẹn ba ṣe di rogodo (Omọ yẹn ba ṣe di rẹbẹtẹ)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
O bembe, o bembe (o bembe, o bembe)
Mo fẹ ka, mo fẹ ka
Nigba ti mo ridi ọmọ yen
Mo fẹ ka, mo fẹ ka
Nigba ti mo ridi ọmọ yen
Sugbon mo laya, mo laya
Mo dẹ gboju le kini tirin yen
Sugbon mo laya, mo laya
Mo dẹ gboju le kini tirin yen
Hmm, so, so
I'm resourceful, dependable
Hmm, so, so
I'm incredible, so durable
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
Omọ yẹn ba ṣe di rogodo (Omọ yẹn ba ṣe di rẹbẹtẹ)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
O bembe, o bembe (o bembe, o bembe)
Emi l'ọba, ọba
Aji f'ọla ji fa
Emi l'ọba, ọba
Aji f'ọla ji fa
Ọmọ meji, mẹta, mẹrin
Lo ma do mi lo gba
Ọmọ meji, mẹta, mẹrin
Lo ma do mi lo gba
Bi kan ṣe n lọ ni kan wa
Wọn gbori wọle
Bi kan ṣe n lọ ni kan wa
Wọn gbori wọle
They like the way, they like the way
I dey cum on them
They like the way, they like the way
I dey give it to them
They like the way, they like the way
I dey make them moan
They like the way, they like the way
I dey make them moan
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
Omọ yẹn ba ṣe di rogodo (Omọ yẹn ba ṣe di rẹbẹtẹ)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
O bembe, o bembe, ye (o bembe, o bembe)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
Omọ yẹn ba ṣe di rogodo (Omọ yẹn ba ṣe di rẹbẹtẹ)
Ọba lo nihun fise (ọba lo nihun fise)
O bembe, o bembe, ye (o bembe, o bembe)
Ọba mi ni sọhun, joor ma gbọ
Alagbẹ bẹ láàfin, Olubadan máa gbọ
Aláàfin of Oyo, Lamidi mi o to pe loruko
Sho ma gbọ, Alagbẹ be láàfin
Isalẹ ọra




9ice - Certificate (Reloaded)
Альбом Certificate (Reloaded)
дата релиза
15-03-2007




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.