Brymo - Alelúyà Méje текст песни

Текст песни Alelúyà Méje - Brymo



Aleluya Méje Méje
Oselu jọ f'ọjọ Méje
Won fẹ tó'lú lójó Méje
Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese
Aleluya Méje Méje
Awon Ojelu Ferege
Won L'awọn Ọmọ Yepa Tún Ti De
Wọn fẹ dá'lúrú m'èrè
Aleluya Méje Méje
Akonileru Wọn Tún Ti De
Wọn Fẹ sọ bo'ṣè máa Gbe
Iwo F'okun S'ọrun òun Ṣiṣẹ Agbe
Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese
Wọn L'awọn Omidan m'àiyé
Wọn Fe Jeka, Wọn Fẹ Roso
Oko m'àiyé Ọkùnrin
B'oko Waju Si e K'ota
Bo Ba K'eyin Si e K'ota
Bo Ba 'wọ Nìkàn Se Ohun Olese
Ma gbàgbé ibí O Ti n'babọ' o
B'oko Waju Si e K'ota
Bo Ba K'ẹyin Si e K'ota
Bo Ba Kuwo Nìkàn Se Ohun Olese
Ma gbàgbé ibí O Ti n'babọ' o
Aleluya Méje Méje
(Arere epa epa)
Adaleru Won Tun Ti De
(Arere epa epa)
Kofe k'ọmọ O mo Bàbá Rẹ
(Arere epa epa)
Kofe k'ọkọ O gbọ t'àyà rẹ
(Arere epa epa)
Gbogbo Iṣẹlẹ Korin-kese
(Arere epa epa)
Won L'awọn Omidan Lomayele
(Arere epa epa)
Wọn Fe Jeka Wọn Fẹ Roso
(Arere epa epa)
Oko m'àiyé Ọkùnrin
(Arere epa epa)
Eh ya yah ya...



Авторы: Olawale Olofo'ro


Brymo - 9: Èsan
Альбом 9: Èsan
дата релиза
08-09-2021




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.