Brymo - Òkùnkùn текст песни

Текст песни Òkùnkùn - Brymo



N ò fara pamọ′ fún òló mi
Èé ṣe t'ọ′rọ' rẹ ń fún mi
N ò ṣ'olùgbàlà
Òótọ′ dùn mo wárí o
Káwọn ọ′rẹ' mi mi yọ lódodo
Ìfẹ′ nìkan fún mi
s'ẹnìkan mi yọ
Àjò layé
N ò mọ mo ṣe o
Mo fura ibẹ′ ni ń lọ
Òkùnkùn lati
Òkùnkùn ń lọ



Авторы: Olawale Olofo'ro


Brymo - 9: Èsan
Альбом 9: Èsan
дата релиза
08-09-2021




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.