Brymo - Adédọ̀tun текст песни

Текст песни Adédọ̀tun - Brymo




Awon adan fo loke
Won foka si oju orun
Won o ma mo ibi won lo
Eledua lo n shey ike won
Ko keyin si é, oré o
O hun o n wa
O wa ni waju re
Adedotun—
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba gberin
Adedotun o
Awon adan fo loke
Ni igba, igba
Won kun oju orun
Won o ma mo iwun wan n je
Eledua lo n sho won
Lo n bo wan
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O wa lo Sokoto
O wa lapo sokoto
Adedotun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba ngberin
Adedotun o
Adedotun
Oyindamola mi
Ero gbogbo e ba ngberin
Adedotun o
Ko pamo si é
Oré ooooooo
O hun o n wa
O wa ni waju re o



Авторы: Olawale Olofo'ro



Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.