DJ Neptune - Ololufe (feat. Wande Coal) [Mixed] текст песни

Текст песни Ololufe (feat. Wande Coal) [Mixed] - DJ Neptune




Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem!)
Hmm, sọ fun wọn mo n'ifẹ
Mo ni, "Fọlashade"
Sọ fun pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni o
Layẹmi, Olayẹmi, mo n'ifẹ
Funkẹ, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Titilọla, hmm, sọ fun ẹ, "Mo n'ifẹ"
Mo ni, "Fọlashade"
Sọ fún pe mo n'ifẹ, mo n'ifẹ gan ni
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ re
Ko, ko, ko, ko
Konkobilo, ko, ko, ko
O fẹ pàdé ìsàlẹ
Ò yẹ fún konkobilo
Ko, ko, ko, ko
O wa fẹ jẹ ko, ko, ko, ko
Moni ko pàdé ìsàlẹ
Ìyẹn gan lo n ṣe ko-ko
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ
Iwọ l'ololufẹ, my darling
Iwọ l'ololufẹ mi, mo n'ifẹ rẹ (giddem...)



Авторы: Simisola Bolatito Ogunleye


Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.
//}