Monique - Ride On текст песни

Текст песни Ride On - Monique



Agbára Olórun mbe níbí.
The Power of GOD is here.
Èmí Olórun mbe níbí.
The Spirit of GOD is here.
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn.
Momòpé bímobá bérè, Á sògo.
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow.
Ride On, Ride On, Ride On.
Èmí oooo.
Ride On, Ride On, Ride On.
Agbára Olórun mbe níbí.
The Power of GOD is here.
Èmí Olórun mbe níbí.
The Spirit of GOD is here.
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn.
Momòpé bímobá bérè, Á sògo.
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow.
Ride On, Ride On, Ride On.
Èmí oooo.
Ride On, Ride On, Ride On.
Let my ears belong to you so all i hear is you.
Let my heart belong to you.
So all i do is you.
Shield me from the power of sin.
Let them gat nothing on me.
Holy Spirit, gbàmí tán.
Momòpé bímobá képè é, Óma foùn.
Momòpé bímobá bérè é, Á sògo.
I know that the Spirit of GOD will cause an overflow.
Ride On, Ride On, Ride On.
Èmí oooo.
Ride On, Ride On, Ride On.
Agbára Olórun mbe láyé mi.
Agbára tóh borí ohun gbogbo.
Who art thou oh mountain níwájú Oba ayéráyé ayé.
Olúwa tóh nípá àti agbára.
Òkan soso òrò nso gbogbo òrò.
Òrò gbénú omi adágún dáke
Òrò gbénú omi òkun
Òrò tin gbe áwon orun nìse
Ìjìnlè nlá Atófaratì òkè.
Mopá tàsetàse L'órúko JÉSÙ Kristì.
Egbé oríiyín sókè, èyin enu ònà,
asì gbé e yín sókè èyin ilèkùn ayérayé, Oba ògo kíó wolé wá.
Àkóbí àwon òkú, òdó àgùntàn tíó fèmí lé'lè fún wa.
Olùdámòràn, igi òkìkí, àpáta aìí dìgbòlù, òkè táò l'esí.
Òjìjí àti ìmólè.



Авторы: Michael Abdul


Monique - Ride On - Single
Альбом Ride On - Single
дата релиза
15-03-2020




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.