Oluwalonibisi - Yoruba Hymns текст песни

Текст песни Yoruba Hymns - Oluwalonibisi



E je k'a f'inu didun
Yin Oluwa olore
Anu Re yio wa ti
L'ododo daaju daaju
On nipa agbara Re
F'imole s'aiye titun (E je ka jo ko)
E je k'a f'inu didun(K'a f'inu didun yin Oluwa)
Yin Oluwa olore(A gba 'ni, a ji 'ni, a la 'ni, a gba 'ni)
Anu Re yio wa ti (Alaanu to po)
L'ododo daaju daaju
E yo ninu Oluwa, e yo
Eyin t'okan re se dede
Eyin to ti yan Oluwa
Le 'banuje at'aro lo(E ba mi yo o)
E yo!(Ninu Oluwa) E yo!(E maa yo titi aye)
Eyo n'nu Oluwa e yo!
E yo! E yo!(Ayo da?)
Eyo n'nu Oluwa e yo!
(E gbo naa)'Gba t'a ba nja ija rere
Ti ota fere bori wa
Ogun Olorun t'e kori
Po ju awon ota yin lo
E yo! E yo!
Eyo n'nu Oluwa e yo!
E yo!(Bibeli lo so bee) E yo!
Eyo n'nu Oluwa e yo!
(T'o ba ri bee) A f'ope f'Olorun
L'okan ati ohun wa
Eni s'oun 'yanu
N'nu eni t'araye n yo
Gbat'a wa l'om'owo
On na l'o ntoju wa
O si f'ebun ife
Se 'toju wa sibe
K'a f'iyin on ope
F'Olorun Baba, Omo
Ati Emi mimo
Ti o ga julo l'orun
Olorun kan lailai
T'aiye at'orun mbo
Be lo wa d'isiyi
Beni y'o wa lailai(Give Him your praise, Halleluyah!)
(Oya) Mo m'ope mi wa, f'Oba rere to da mi si
Emi Oluwalonibisi, mo wole, juba fun
Emi wa n k'alleluya si
Bi gbogb'aye dite mo wa
Won gbodo te'ri ba fun Oluwa
Eyin omo ijo mimo
E dide e yin Oluwa
Alleluya ni orin wa
Alleluya wa ninu ise wa
Bi aye fe, bi aye ko
Won te'ri ba fun Oluwa
Alleluya ni orin wa
Alleluya wa ninu ise wa
Bi aye fe, bi aye ko
Won te'ri ba fun Oluwa
B'oruko Jesu ti dun to
Ogo ni fun oruko Re
O tan 'banuje at'ogbe
Ogo ni fun oruko Re
Ogo f'oko Re, ogo f'oko Re
Ogo f'oruko Oluwa
Ogo f'ooko Re, Ogo f'oko Re
Ogo f'oruko Oluwa
Okan mi nyo ninu Oluwa
'Tori O je iye fun mi
Ohun Re dun pupo lati gbo
Adun ni lati r'oju Re
Emi nyo ninu Re (Ibanuje o i mo, ayo l'o ku)
Emi nyo ninu Re
'Gba gbogbo lo nf'ayo kun okan mi (O f'ayo kun mi)
'Tori emi nyo n'nu Re
Ehehn, oya, bere mo'le k'a jo yin
Gbogbo eniyan ka'a ma jo
Wa yin Jesu ma ti'ju
K'a 'wo e s'oke k'a gbe ga
Waa ri wonder ninu ope
Ibanuje re a fo lo(ah)
Ekun, ose a sa lo(ehh-eh-eh)
Oluwa orun on aiye
'Wo n'iyin at'ope ye fun
Bawo l'a ba ti fe O to
Onibu-ore
Onibu-ore
Onibu-ore
Bawo l'a ba ti fe O to
Onibu-ore
Onibu-ore
Onibu-ore
Bawo l'a ba ti fe O to
Onibu-ore
Iwo t'O fe wa l'a o ma sin titi
Oluwa oloore wa
Iwo t'O yo wa ninu 'danwo aye o
Mimo l'ogo ola Re (Baba, Iwo nikan)
Baba, Iwo la o ma sin (Ko s'elomiran, Iwao nikan la f'ope fun o)
Baba, Iwo la o ma bo (A f'iyin, f'ogo f'oruko yin Sir)
Iwo t'O fe wa l'a o ma sin titi
Mimo l'ogo ola Re (Baba, Baba Iwo nikan ni)
Baba, Iwo la o ma sin (Ijo e da? K'o fo s'oke, k'o yin Jesu)
Baba, Iwo la o ma bo (Iwo, Iwo, Iwo, Iwo, Iwo)
Iwo t'O fe wa l'a o ma sin titi
Mimo l'ogo ola Re
Emi yoo k'okiki Re Oluwa
Iwo ni o da mi dide
Iwo ni oo je ki ota yo mi
Ogo ni f'oruko Re
Iyin, Ọla, Ogo ni fun
Agbara ati ipa jẹ Tirẹ
Ẹgbẹrun ahọn ko to yin
A wolẹ, a juba Rẹ
Iyin, Ọla, Ogo ni fun
Agbara ati ipa jẹ Tirẹ
Ẹgbẹrun ahọn ko to yin
A wolẹ, a juba Rẹ
Iba se pe Oluwa
Ko ti wa ni tiwa
Lo ye k'awa ma wi
Nigbat' esu gbogun dide
Ope ni f'Oluwa, oba wa Olore
E se 'ba kabiyesi, kabiyesi le
A f'ope fun Jehovah
To gba wa lowo ota
A dupe Oluwa (Oya ba mi f'ope fun o)
Ope ni f'Oluwa, oba wa Olore
E se 'ba kabiyesi, kabiyesi le
A f'ope fun Jehovah
To gba wa lowo ota
A dupe Oluwa
(S'e ri) Oluwa wa fun wa, bi akoni eleru
Oun l'olori ogun
Arogun ma ti di
Arogun ma s'ojo
(Ah) Gbogbo eyin oke, kekere at nla, eyi to n gba gudu mo mi
E ma wa riri, ni'waju Oluwa




Oluwalonibisi - Hymns to Him
Альбом Hymns to Him
дата релиза
28-05-2016


Еще альбомы
Исполнитель Oluwalonibisi, альбом Come to Me
2013
все альбомы


Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.