Tim Godfrey - Oriki текст песни

Текст песни Oriki - Tim Godfrey



ORIKI
:
Ka-biyesi atoperi Eledumare mi se
Ka-biyesi agba nla atoperi Eledumare mi se
Baba mi awimayehun, Baba mi awilese
Baba mi aselewi, Baba mi, Baba nla ti ngbani
Gbani Gbani lojo isoro, eleti gbohun gbaroye
Afetilukara bi ajere, eru jeje leti okun pupa
Oba to tele bi eni nteni, Ota somo bi eni taso
Gbongbo idile Jesse ti ko le ku lai
:
Eyin loba to nse oun gbogbo lodu
Eyin lakoda, eyin laseda, eyin laweda
Eyin lameda, ogbagba tirin gbagba
Alagbada ina, alawotele oorun
Alade gbedegbede bi eni n layin
Edumare moti mope mi wa feni tope ye fun
Moti fiyin feni tiyin se tire o
Eni to n se mimo, to n je mimo, to n mu mimo
To n gbe bi mimo, to niwa mimo, Alade ogo
Talaba fi o we, na you bi ano, na you bi oni
Na u tuni lola, ope ye o o Baba, Edumare gbope wa
Tire ni o, tire ni o
Mo fi sile fun o
Females: Owuro mi, osan mi, ale mi o o
Tire ni Oluwa
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Tire ni o/7x
(Modulation)
Call- my praise
Resp: my praise
Call- Belongs to you
Resp: Belongs to you
Call: Ese
Resp: Ese
Call: Adupe o
Resp: Adupe o
Call: Igwe/6x (nna naba me)
Resp: Igwe



Авторы: Timothy Chukwudi Godfrey


Tim Godfrey - Sound Check
Альбом Sound Check
дата релиза
26-07-2011




Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.