Текст песни Ayo - Tope Alabi
Aye
le
O
ibosi
O
Aye
dorikodo,
koyeni
Mo
Ibo
Lan
lo
eniyan
osuni
ye
Ibi
Taba
ma
gba
O
koyeni
Yan
O.
Aye
ma
le
ibosi
oooo
Chrs:
. Aye
le
O
ibosi
O
Aye
dorikodo,
koyeni
Mo
Ibo
Lan
lo
eniyan
osuni
ye
Ibi
Taba
ma
gba
O
koyeni
Yan
O.
Eniyan
E
so
fun
mi
nibo
lanlo
gan
Lomode
at'agba
awa
deni
tio
gbonmo
Benikan
ba
se
rere
elomiran
asebi
Onse
mi
on
gba
mi,
Lan
se
dupe
lowo
Eni
ton
seni
Iberia
Olorun
kosi
lokan
aye
Mo
Ibosi
tan
fele
ke
koje
kami
or
Iya
Ni
Nibo
Lan
re?
Chrs:
Aye
le
O
ibosi
O
Aye
dorikodo,
koyeni
Mo
Ibo
Lan
lo
eniyan
osuni
ye
Ibi
Taba
ma
gba
O
koyeni
Yan
O.
Aimoye
igbeyawo
Lori
sanpan
Awon
tofife
bere
won
to
donikorira
Abi
osi
nije
tani
Mo
ri,
Owo
lonje
Mo
ba
E
tan
Ise
sopo
omobinrin
dalagbere,
okunrin
njawo
ka
Alafowofa
Omo
arise
mase
oku
ole
lo
berebe
Baba
ojomo
loju
Mo,
otoju
Suni,
Eje
ka
Tero
ara
wa
pa
Abi
bio
se
ma
lo
niyi
o?
Aye
O
E
Dami
loun.
Chrs:
Aye
le
O
ibosi
O
Aye
dorikodo,
koyeni
Mo
Ibo
Lan
lo
eniyan
osuni
ye
Ibi
Taba
ma
gba
O
koyeni
Yan
O.
Opo
Omo
ti
so
obi
donirewesi
Olukoni
atakeko
to
dota
ara
won
Tori
Aja
to
yo
kole
balai
yo
sere
Awon
to
wa
kawe
ti
won
orise
se
nko?
Opo
agbanisise
tio
baba
won
sepo,
konigbawon
sise
Ese
wan
gori
ese
lo
Aye
Jese
tan
O
won
tun
gufe
ese
Jade
Iborisa
ati
Osho
laye
fin
jeun
Ori
olori
apa
alapa,
odididi
Omo
tuntun
aboyun
dawati
nigboro.
Eni
towo
moto
elero
jade
Nile
Ole
mo
pada
wale
Mo
Ibi
ikoko
ara
won
di
fifa
lo
Kaboni
lowo
iyen
tun
dogun
Kowa
seni
tose
fokan
tan
mo
Ara
Aye,
igbawo
lafe
sheyi
da
O?
Egbo
Na
se
samama
wo
Ni
koyeniyan
O
Aye
le
O
ibosi
O
Aye
dorikodo,
koyeni
Mo
Ibo
Lan
lo
eniyan
osuni
ye
Ibi
Taba
ma
gba
O
koyeni
Yan
O.
Gbogbo
ijo
Olorun
Ni
gbogbo
agbaye
Oro
yi
kanwa
O
Ema
laju
sile
Ki
talubo
okowo
O
Eje
Ka
gbadura
Bo
senlo
yi
kosunwon
Wiwa
alafia
orile
ede
yi
gbodo
jewa
logun
Gege
bi
onigbagbo,
eje
kaje
apere
rere
Awa
loye
ka
bere
Gbo
orile
ede
wa
adura
ko
Mo
E
Lori
Kolorun
gbase
lowo
esu
ton
fogun
Mo
O
Korire
Ma
gbabode
kio
gba
atunse
Ile
Nigeria
bere
si
Ni
se
rere.
Gbo
orile
ede
wa
adura
ko
Mo
E
Lori
Kolorun
gbase
lowo
esu
ton
fogun
Mo
O
Korire
Ma
gbabode
kio
gba
atunse
Ile
Nigeria
bere
si
Ni
se
rere.
Ilu
ibile
mi
Ibi
agbe
fori
mi
sole
oya
ma
Kore
ran
Mi
O,
orilede
wa
O
bere
sini
se
sere
Origun
mererin
Ile
yi
Ma
gboro
Oluwa,
se
rere
eeeee
Ile
Nigeria
kio
gba
atunse.
Ese
toti
lere
Sa
Jesu
darijini
kire
ma
a
Bo,
sun
wa
bo
Orile
ede
wa
O,
bere
sini
se
rere
Gbogbo
eniyan
to
n
be
nibe
emagba
alafia
Olorun
ire
kowole
wa
Ile
Nigeria
kio
gba
atunse.
Gusu
ariwa
Ila
orun
iwo
re,
oya
ma
Ko
ibodi
Mo
n
so
Orile
ede
wa
O,
bere
sini
se
rere.
Amin
O
Beni
Kori
se
rere
kenikeni
mase
Dio
lowo
(Amin)
Ile
Nigeria
kio
gba
atunse.
1 Imole De
2 Logan Ti O De
3 Awa gbe o ga
4 All the Glory
5 Iwo Lawa O Ma Bo
6 Kabi o osi
7 No One Else
8 Eru Re To Ba
9 Olowo Ina
10 We Have Come
11 Emi Mimo
12 Oba mi De
13 Ayo
14 War
15 Alayo
16 Adonai
17 Angeli
Внимание! Не стесняйтесь оставлять отзывы.