King Sunny Ade - Orisun Iye paroles de chanson

paroles de chanson Orisun Iye - King Sunny Ade



Orisun Iye
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Orisun Iye
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
B'odun ba ti de o
Emi a m'owo ikore mi wa
B'odun ba ti de o
Emi a mowo ikore mi wa fun o
Iwo l'orisun iye tin fun ni layo
Orisun iye tin fun ni layo o
Opo lo s'odun to k'oja
Won o si l'aye mo loni
Opo lo ti s'odun to k'oja
Won o si l'aye mo loni
Kii s'epe a fi yo won o
Afi n'gb'oruko Re ga ni Baba wa
Orisun Iye (Baba wa)
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Orisun Iye
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Baba pe'mi l'ayo
K'emi 'le mowo ikore mi wa
Baba pe'mi l'ayo
K'emi 'le mowo ikore mi wa
Fun o
Iwo l'orisun iye tin fun ni layo
Orisun iye tin fun ni layo o
Opo lo s'odun to k'oja
Won o si l'aye mo loni
Opo lo ti s'odun to k'oja
Won o si l'aye mo loni
Kii s'epe a fi yo won o
Afi n'gb'oruko Re ga ni Baba
Orisun Iye
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Orisun Iye (Baba wa)
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Instrumental Interlude
Orisun Iye
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san
Orisun Iye (O n'gbo mi)
Oba alase
Jesu mo be o o
Je kin ro wo ikore san



Writer(s): King Sunny Ade


King Sunny Ade - E Dide (Get Up)
Album E Dide (Get Up)
date de sortie
29-07-2008




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.