King Sunny Ade - Ose Ose paroles de chanson

paroles de chanson Ose Ose - King Sunny Ade



Oṣe, ọṣẹ o baba
Oṣe, ọṣẹ o baba
Iwọ to f'ẹmi l'afẹtan
To fi'ṣẹ iyanu rẹ han nínú ayé mi
Oṣe, ọṣẹ o baba
Waan ba bori wa pẹlu agbara wan
Mo f'oluwa b'ẹsẹ sẹ di mi lo sọ mi aṣẹgun
Ọba a funi ma si regun
Ẹni mi yọ sori rẹ
Oṣe, ọṣẹ o ọba onibu ọrẹ
Oṣe, ọṣẹ o baba(halleluyah)
Oṣe, ọṣẹ o baba
Iwọ to f'ẹmi l'afẹtan
To fi'ṣẹ iyanu rẹ han nínú ayé mi
Oṣe, ọṣẹ o baba
Iwọ ọkan mi
Iwọ ọkan mi
Iwọ ọkan mi
Iwọ ọkan mi
Ko máṣe gbagbe ore Oluwa o
Ko fi gbogbo oun to o ni gbe Oluwa ga
Fi'bùkún f'oluwa o
Iwọ ọkàn mi
Ko máṣe gbagbe ore rẹ lori mi
Fi'bùkún f'oluwa o
Iwọ ọkàn mi
Ko máṣe gbagbe iṣẹ ìyanu rẹ
ban dana so fún bàbá o
Iyin ògo fún saati ọba
ban dana so fún bàbá o
Iyin ògo fún saati ọba




King Sunny Ade - E Dide (Get Up)
Album E Dide (Get Up)
date de sortie
29-07-2008




Attention! N'hésitez pas à laisser des commentaires.