9ice - I Cancel Lyrics

Lyrics I Cancel - 9ice



Ṣe borí ń buja
Orí ẹní lo ń wolé deni
Ti, Anscestor o
Ìbílẹ, milẹ, milẹ, milẹ, milẹ, ti
Ibí t'ẹgbẹ ń náwó, jẹ nara ń be o
(Ibí t'egbé ń kólé) jẹ kan ra ń bẹ o
I shall never, never work in vain
I shall never, wallow in disgrace
I cancel, I cancel, bad things for my life, I cancel
I cancel, I cancel, ex wey dey make me cry, I cancel
Mo cancel, mo cancel, aṣérì mo cancel
Mo cancel, mo cancel, ìdíbàjẹ́ mo cancel
Wọn mo ṣíṣẹ títí, wọn s'ere
Aje, jọ, gbàyí, iṣẹ ko lére
Ìṣẹ kọ lówó, témi ye mí, témi ye mí, ahh
Olùwà come bless me without condition
ìgbàgbọ' without solution
Make dem bring confusion with Devil's formation
Ìwọ l'Oluwa mí, perfect solution
I shall never, never work in vain
I shall never, wallow in disgrace
I cancel, I cancel, bad things for my life, I cancel
I cancel, I cancel, ex wey dey make me cry, I cancel
Mo cancel, mo cancel, aṣérì mo cancel
Mo cancel, mo cancel, ìdíbàjẹ́ mo cancel
T'ayé ń j'àyé, ta'yé wa ṣì tún ń j'àyè mọ
E lẹ o rí, ohùn lẹ o gbọọ
I lead by grace, so many supplications
Multiply by God's decision
I am a success with global commission
(It's Bizzle on the mix, on the mix)
mo cancel
Aje tọ jẹe



Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Album Afro Juju
date of release
17-12-2022




Attention! Feel free to leave feedback.