9ice - Murebo Lyrics

Lyrics Murebo - 9ice



(It's Protunez on the beat)
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ oo-oh
Owó wọlé o, ire
Olá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́ mo jẹ à f'ẹran kọ
beer ṣeré
beer ṣeré
Lager beer ṣeré pá, lábé wire, ṣeré
Don't be a stupid man o
Life is full of ups and down
If you dey enjoy, brother, appreciate your grace
Àwọn ń bẹ nílé, jẹ kàn t'arà rẹ gain
Time to enjoy, brother, make you no dey play
Be'wù b'ẹnlé, f'olè ṣọ gate
Stop playing!
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo rẹ o, murebọ oo-oh
Owó wọlé o, irẹ dé, olá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́ mo è jẹ à f'ẹran kọ
beer ṣeré
beer ṣeré
Lager beer ṣeré
Lábé wire, ṣeré
Òbí, mù'ré
yín f'Olùwà, àṣírí yìn lọ ń bẹrẹ ńbo
Dem be dey check, but dem dey collect
Who dey checker? Dem go collect
Dem dey spend náírà, we dey spend dollar
Bo ṣe cefa, a sọdì paper
Ògo Olùwà ní, don't take it personal
I love my beer, odún lénu proper
Stop playing!
Àjò to re o, murebọ o
Àjò to re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ o
Àjò mo re o, murebọ oh
Owó wọlé o, irẹ dé, olá wọlé o, ọmọ
Ẹlẹgbẹ́ mo è je à f'ẹran kọ
beer ṣeré
beer ṣeré
Lager beer ṣeré
Lábé wire, ṣeré
(It's Bizzle on the mix)



Writer(s): Alexander Abolore Adegbola Akande


9ice - Afro Juju
Album Afro Juju
date of release
17-12-2022




Attention! Feel free to leave feedback.